Ìbànújẹ́ kò sí fún ẹnikẹ́ni mọ́ ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa...
Ọpẹ́lọpẹ́ Olódùmarè tó wípé ní déédéé ìgbà yí àti ní déédéé...
Bí a ò kú, ìṣe ò tán Láìsí ìmọ́tótó agbègbè àti...
Màmá Ìran Yorùbá, Ẹni tí Olódùmarè rán sí wa láti ṣe...
Ní gbogbo ìgbà ni àwa ìran Yorùbá yóò máa fi ọkàn...
Nínú àwọn àlàkalẹ̀ ètò ìṣàkóso orílẹ̀ èdè D.R.Y tí Olódùmarè jogún...
Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the...
Akí gbogbo àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P)...
Gbogbo àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) ti...
Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, ètò ẹ̀yáwó tí kò...
Ní àìpẹ́ yí ni Ìyá Wa, Olùgbàlà tí Olódùmarè rán sí...
Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the...
Màmá Ìran Yorùbá, Olùgbàlà tí Olódùmarè rán sí àwa ọmọ ìbílẹ̀...
Ìkan nínú ọ̀rọ̀ tó ṣe gbòógì tó pè fún àkíyèsí, tí...
Láti ìgbà ìwásẹ̀ ni àwọn babańlá wa ti ń lo ọgbọ́n...
Màmá wa, Ìránṣẹ́-Olódùmarè sí Ìran Yorùbá, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, tún ti...
Orílẹ̀ èdè tó bá ti sọ èdè rẹ̀ nú yóò parun,...
Nígbà tí àwọn amúnisìn ti wá sí ilẹ̀ Yorùbá, tí wọ́n...
Tí ò bá sí olè ilé, olè ìta kò le jà!...
Ànfààní tí ó wà fún Ọmọ-Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P)...
Tí Olódùmarè bá ti ṣí’jú wo’ni, àyọ̀ ayérayé ni ó máa...
Ní Orílẹ̀ èdè Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y, gbogbo wa...
Oníṣègùn Ìtọ́jú-Àwọn-Ọmọdé kan, ní ìlú Ìbàdàn, Democratic Republic of the Yoruba...
Ní ìgbà ìwáṣẹ̀, kí àwọn amúnisìn tó wá so irun iwájú...
Fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ni orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic...
Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the...
Ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lẹ́nu ọjọ́ mẹ́ta yí, ó kọjá à...
Ní gbogbo ìgbà ni àwa ìran Yorùbá yóò máa dúpẹ́ lọ́wọ́...
Láti ìgbà láíláí ni àwọn Ọba ilẹ̀ Yorùbá ti jẹ́ ọ̀dàlẹ̀,...
Èdùmàrè máṣe jẹ́ kí á fi ìpìlẹ̀ ayé wa lé orí...
Ìṣètò Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba,...
Ní àìpẹ́ yí ni Màmá wa, Iyá Ìran YORÙBÁ , Ìyá...
Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the...
Gẹ́gẹ́ bí orin tí a má ń kọ nígbà dé ìgbà...
Ní Orílẹ̀-èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá,...
Ètò ìṣèlú ní Orílẹ̀ Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic...
A dúpẹ́ lọ́wọ́ Olódùmarè fún àánú rẹ̀ lórí ayé ìran Yorùbá,...
Láti ìgbà ìwáṣẹ̀ ní àwọn ọba ilẹ̀ Yorùbá kò ti ní...
Òrọ̀ ti jáde o! Àṣẹ sì ti gùn-ún, nípa ilé-ìwé ní...
Olódùmarè fi ọrọ̀ rẹpẹtẹ dá ilẹ̀ Yorùbá lọ́lá, Ó fún wa...
Lẹ́hìn tí àwọn amúnisìn ti ríi dájú pé, àwọn ti ṣẹ́gun...
Tí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa orílẹ̀ èdè tí Olódùmarè kẹ́...
Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, máa nsọ àwọn gbólóhùn ọ̀rọ̀ kan...
Lẹ́yìn tí àwọn òyìnbó amúnisìn ti gbàkóso ìṣèjọba ilẹ̀ Yorùbá tán,...
Ilẹ̀ Yorùbá jẹ̀ orílẹ̀ èdè olómìnira aṣèjọba ara ẹni láti ìbẹ̀rẹ̀...
Orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá,...
Nínú àwọn ọ̀rọ̀ tí Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá máa ń...
Lóotọ́ àti ní Òdodo, a ti dé ibi tí a nlọ...
Ọ̀rọ̀ ètò ààbò jẹ́ ohun pàtàkì tí a kò sì gbúdọ̀...
Ọba ‘bìnrin ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ní ó ndarí ìlú agbèsùnmọ̀mí nàìjíríà fún...
Káàkiri àgbáyé ni wọn yóò ti mọ orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa...
Ṣébí Yorùbá ló sọ pé ibi tí a bá ti pè...
Màmá Ìran Yorúbá, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ti máa nfi yé wa...
Àtunbọ̀tán ìwà ìkà àti ìjẹgàba àwọn amúnisìn ṣi kù lára àwọn...
Ọ̀kan lára àwọn àǹfààní tí a óò jẹ ní Orílẹ̀ èdè...
Àfojúdi, ìgbéraga àti àìmọ̀kan wà lára ọ̀ràn tí ó bá ìlú...
Ìran mi kò ní parun láéláé!” Gbólóhùn yí jẹ́ ọ̀kan gbòógi...
Àìmọ̀ máa njẹ́ kí ohun tí a kò mọ̀ ó ṣe...
Ní Orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the...
ÀDÚRÀ: OLÓDÙMARÈ, ALÁGBÁRA TÍ Ó GA JÙLỌ, PA GBOGBO Ọ̀TÁ RUN...
Ọjọ́ tí pẹ́ tí àwọn amúnisìn tí ń huwà búrúkú sì...
Nígbà tí Olódùmarè ṣẹ̀dá ìran Yorùbá, Ó fún wa ní èdè...
Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ìgbà ni Màmá wa, Ìyá-Ìran Yorùbá, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ti...
Iṣẹ́ ni oògùn ìṣẹ́, ìgúnpá sì ni ìyékan ẹni. Ní Orílẹ̀...
Ní ìgbà àtijọ́, àwọn ọba ní olórí ìjọba ní ilẹ̀ Yorùbá,...
Àgbà kìí wà lọ́jà k’órí ọmọ tuntun ó wọ́, bí àwọn...
Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítiri-Abíọ́lá, ti fi ọ̀rọ̀ ránṣẹ́ sí àwọn...
Tí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa orílẹ̀ èdè tí Olódùmarè dá...
Látètèkọ́ṣe ti àwọn amúnisìn bẹ̀rẹ̀ láti ma wá s’órílẹ̀ Yorùbá láti...
Orílẹ̀-Èdè jẹ́ àwọn ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ènìyàn tí wọ́n jẹ́ ìran kan-náà; èyí...
Ní Orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the...
Ohun tí ó jẹ́ ètò-àtọwọ́dá ọmọ-ènìyàn; ètò àtọwọ́dá àwọn òyìnbó-amunisìn, njẹ́...
“Mò ń bínú sí ara ìlú” Kí ló gbé ọ̀rọ̀ yi...
Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the...
Ẹ wo Seyi Makinde nínú àwòrán tí ẹ̀rọ ayélujára gbée níbi...
Orí ni ẹja ti ń bàjẹ́, tí orí ẹja bá ti...
Ọmọbìnrin kan tí a rí fídíò rẹ lórí ayélujára X, ló...
Ìròyìn tí a rí kà lórí ẹ̀rọ ayélujára X fi àwòrán...
Nígbà gbogbo ní àwa ìran Yorùbá yóò máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ẹlẹ́dàá...
Afẹ́fẹ́ ti fẹ́, a ti ri ibi tí adìyẹ fi nṣe...
Ẹ wò bí Nàìjíríà ṣe sọ àwọn ọmọ kéékèèké dà, àwọn...
Ìròyìn kan ní a rí lórí ayélujára tí o un sọ...
Ìyàwó ilé kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Barkisu Sulaiman ní...
Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the...
Ṣèyí Makinde aláìmọ èyí tó kàn ṣáà ń dá ọ̀ràn kún...
Ìròyìn kan g’óri afẹ́fẹ́ lát’orí ayélujára nípa àwọn òṣìṣẹ́ fún ìlú...
Nínú fọ́nrán kan ni a ti rí ọkùnrin tó nà gbalaja...
Ẹnikan tí wọ́n pe orúkọ rẹ̀ ní Ọ̀mọ̀wé Garus Gololo ni...
Ètò Ẹ̀kọ́ ṣe pàtàkì ní Orílẹ̀-Èdè. Ṣebí kò sí ohunkóhun tí...
Ohun tí ó bá wu ènìyàn ni ó lè fi ìgbé-ayé...
Ìròyín tí a rí lórí ẹ̀rọ ayélujára X, ìkànnì @SaharaReporters, sọ...
Kò ní dáa fún àwọn ọ̀bàyéjẹ́, olóṣèlú àti gbogbo àwọn amúnisìn...
Ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ nkan ni àwọn òyìnbó amúnisìn ti yí mọ́ wa lọ́wọ́:...
Ọ̀rọ̀ ogun àgbọ́tẹ́lẹ̀ ni o, wọ́n ní kìí pa arọ (tó...
Báwo ni ìbá ṣe dùn tó, ẹ̀yin Ọmọ Igbó-Ọrà, tí ó...
Àwọn àdúrà tó ṣe kókó tí a máa ń gbà tí...
Èmi àti àwọn tó wà ní ipò ìsèjọba pẹ̀lú àwọn ọlọ́pàá...
Láti ìgbà tí Olódùmarè ti dá ìran Yorùbá ló ti fún...
Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, ti máa nsọ fún wa pé...
Tani ó wó àgọ́ ọlọ́pàá tó wà ní Fálọmọ ní ìlú...
Orílẹ̀-Èdè Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ Orílè-èdè Tuntun Olómìnira lati ọjọ Jimọ, ọjọ Kejìlá ti Oṣu Kẹrin (Ìgbé) ọdún 2024. Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ́ 17th ní Iwọ-oòrùn Áfíríkà, Orílẹ̀-èdè 55th ní Áfíríkà, ati Orílẹ̀-èdè Tuntun ni Àgbáyé. D.R.Y jáde kúrò, o sí farahàn ni àlàáfíà nipasẹ ìwé àdéhùn Àjọ Àgbáyé (UN) lorí ẹtọ ọmọ ènìyàn, àwọn ẹtọ ìpinnu-lọkan ara ẹnì fún idà dúró gẹgẹ bi orílè-èdè.
© Copyright 2024 Nípasẹ̀ Alákóso Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá