Orílẹ̀-Èdè Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ Orílè-èdè Tuntun Olómìnira lati ọjọ ẹ̀tì, ọjọ kejìlá ti oṣu kẹrin (Igbe) ọdún 2024. Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ́ 17th ní Iwọ-oòrùn Áfíríkà, Orílẹ̀-èdè 55th ní Áfíríkà, ati Orílẹ̀-èdè Tuntun ni Àgbáyé. D.R.Y jáde kúrò, o sí farahàn ni àlàáfíà nípasẹ̀ ìwé àdéhùn Àjọ Agbaye (UN) lorí ẹtọ ọmọ ènìyàn, àwọn ẹtọ ìpinnu-lọkan ara ẹnì fún ìdadúró gẹgẹ bi orílẹ̀-èdè.
Akọkọ ìrù rẹ rèé tí orílẹ̀-èdè kàn jáde ní àlàáfíà láti di Orílẹ̀-èdè Olómìnira ní Áfíríkà! Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ ìṣẹ ọwọ Ọlọ́run Olódùmarè nípasẹ̀ ìyà wá Olólùfẹ́, Ọlọ́lá-jùlọ, Ọmọ-Aládé Modupẹọla Onitiri-Abiọla (MOA). Èyí jẹ ohun ti o dara lati gbọ ti gbogbo wa si ń ké ihò ayọ sí Ọlọ́run Ọba!
Let's build the cities we are proud of... Work has started in rebuilding our States to world standard.
Ibadan State of the Democratic Republic of the Yoruba Ìpínlẹ̀ Ibadan...
Explore Eko State – The Commercial Nerve Center of the Democratic...
Oyo Empire – The Empire of the Democratic Republic of the...
Ogun State of the Democratic Republic of the Yoruba Ogun State...
Ekiti State of the Democratic Republic of the Yoruba The Ekiti...
Osun State of the Democratic Republic of the Yorùbá Osun is...
Ondo State of the Democratic Republic of the Yorùbá The Ondo...
Orílẹ̀ èdè aşakóso ara ẹni ni Orílẹ̀ èdè Olóminira Tiwantiwa ti Yorùbá, òhun náà ni wọn ń pè ni Yorùbá Nation, Yorùbá Kingdom, Yorùbá Land, Yorùbá Country ní àtijọ́, ó ti di D.R.Y láti ọjọ́ kejìlá oşù igbe egbàáodún-ó-lé-mérinlélógún. Ní báyìí, o ti di ẹsẹ fún ẹnikẹ́ni láti sọ wipé óhún fẹ́ gba Yorùbá Nation nitori kò sí ohun to ń jẹ́ bẹ́ẹ̀ mọ. D.R.Y nikan ló wà, gbogbo wọn ti wà lábẹ́ D.R.Y. ẹnikẹ́ni tó bá pe Yorùbá Nation lái pe D.R.Y, èṣe ni fún irú ẹni bẹẹ. Ohun Yòówù kí o pe Orílẹ̀ èdè Yorùbá lái fi D.R.Y si, ọ̀ràn dídá ni o, yálà o fẹ́ sọọ l’ọrọ ni tabi kọọ lórin, lái fi D.R.Y si, o ti da ọ̀ràn lábẹ́ òfin àgbáyé àti lábẹ́ orílẹ̀ èdè Olóminira Tiwantiwa ti Yorùbá, mi ò mọ̀ kò sí nibe o. Nítorí náà, ẹnikẹni tó bá fé sọrọ nipa orílẹ̀ èdè D.R.Y ko jẹ́ ko mọ ohun lára, kó má pè é ní orílẹ̀ èdè Yorùbá nikan lái fi D.R.Y si. Ibikíbi tí a bá ti gbọ irú ọrọ bée ki ẹni náà mọ wipé ohun ti dáràn!
© Copyright 2024 Nípasẹ̀ Alákóso Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá