Oyo Empire in its core governmental centre stretches from the border with the present-day “Benin Republic” in the West, to the River Niger in the East and North, with the now Oyo, Osun, Ekiti and Ondo Provinces, as well as Benin Empire (still currently within Nigeria) to the South.
Oyo Empire, in the height of its glory, stretched far beyond this ‘governmental centre’, attracting worldwide attention.
Orílẹ̀ èdè aşakóso ara ẹni ni Orílẹ̀ èdè Olóminira Tiwantiwa ti Yorùbá, òhun náà ni wọn ń pè ni Yorùbá Nation, Yorùbá Kingdom, Yorùbá Land, Yorùbá Country ní àtijọ́, ó ti di D.R.Y láti ọjọ́ kejìlá oşù igbe egbàáodún-ó-lé-mérinlélógún. Ní báyìí, o ti di ẹsẹ fún ẹnikẹ́ni láti sọ wipé óhún fẹ́ gba Yorùbá Nation nitori kò sí ohun to ń jẹ́ bẹ́ẹ̀ mọ. D.R.Y nikan ló wà, gbogbo wọn ti wà lábẹ́ D.R.Y. ẹnikẹ́ni tó bá pe Yorùbá Nation lái pe D.R.Y, èṣe ni fún irú ẹni bẹẹ. Ohun Yòówù kí o pe Orílẹ̀ èdè Yorùbá lái fi D.R.Y si, ọ̀ràn dídá ni o, yálà o fẹ́ sọọ l’ọrọ ni tabi kọọ lórin, lái fi D.R.Y si, o ti da ọ̀ràn lábẹ́ òfin àgbáyé àti lábẹ́ orílẹ̀ èdè Olóminira Tiwantiwa ti Yorùbá, mi ò mọ̀ kò sí nibe o. Nítorí náà, ẹnikẹni tó bá fé sọrọ nipa orílẹ̀ èdè D.R.Y ko jẹ́ ko mọ ohun lára, kó má pè é ní orílẹ̀ èdè Yorùbá nikan lái fi D.R.Y si. Ibikíbi tí a bá ti gbọ irú ọrọ bée ki ẹni náà mọ wipé ohun ti dáràn!
© Copyright 2024 Nípasẹ̀ Alákóso Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá