Orílẹ̀-Èdè Yorùbá ní èròngbà à ti sọ ilẹ̀ Yorùbá di àwòkọ́’ṣe ní àgbáyé, pẹ̀lú oríṣiríṣi àwọn ohun am’ayédẹ’rùn fún ará ìlú L’ara ìwọ̀nyí ni ètò ilé-gbígbé fún gbogbo ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá.

Orílẹ̀-Èdè Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ Orílè-èdè Tuntun Olómìnira lati ọjọ Jimọ, ọjọ Kejìlá ti Oṣu Kẹrin (Ìgbé) ọdún 2024. Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ́ 17th ní Iwọ-oòrùn Áfíríkà, Orílẹ̀-èdè 55th ní Áfíríkà, ati Orílẹ̀-èdè Tuntun ni Àgbáyé. D.R.Y jáde kúrò, o sí farahàn ni àlàáfíà nipasẹ ìwé àdéhùn Àjọ Àgbáyé (UN) lorí ẹtọ ọmọ ènìyàn, àwọn ẹtọ ìpinnu-lọkan ara ẹnì fún idà dúró gẹgẹ bi orílè-èdè.
© Copyright 2024 Nípasẹ̀ Ìjọba Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá