• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Alákóso, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y

Ọ̀nà àti Ìgbòkègbodò Ọkọ̀

Ọ̀nà àti Ìgbòkègbodò Ọkọ̀

Orílẹ̀-Èdè Yorùbá ní èto l’ati ṣe ọ̀nà-ìrìn já’kèjá’dò ilẹ̀ Yorùbá, tí ó sì jẹ́ wípé ààbò yíó wà fún ẹnik’ẹni l’ati lọ l’ati apá kan ilẹ̀ Yorùbá sí apá míràn, ìbáà ṣe ní ọ̀gànjọ́ òru, tí kò ní sí ìfòyà kankan rárá.

ọ̀nà-ìrìn já'kèjá'dò ilẹ̀ Yorùbá

Ètò ààbò fún
ẹnik'ẹni