ÀÌSÀN ABÀMÌ NÍ UGANDA
Ìròyìn tí a rí lórí ẹ̀rọ-ayélujára, X, ní ìkànnì @AfricaFactsZone , ni ó gbe jáde o, pé àìsàn tí ó ṣe àwọn ènìyàn ní kàyéfì, torí pé àwọn obìnrin ni àìsàn náà nṣẹlẹ̀ sí, á sì máa mú wọn jó ijó tí wọ́n ò fúnra wọn pinu láti jó, tí kò sì sí onílù tàbí […]