PÀṢÍPÀRỌ̀ ỌMỌ ỌWỌ́
Ó ti dójú ẹ̀ báyìí. Ó sì gba omijé lójú ẹni tó bá mọ iyì ọmọ. Yorùbá bọ, wón ní, ọmọ ni iyì, ọmọ lèrè, ọmọ laṣọ, ọmọ lalẹ́. Ṣùgbọ́n nínú fọ́nrán kan tí a rí lórí ayélujára, ọmọ ọwọ́ oṣù márùn-ún ti wá di ohun tí a nfi ṣe pàṣípààrọ̀ fún ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ ti […]