Olóṣèlú Nigeria Ni Olùgbọ̀wọ́ Àwọn Aṣekúpani, Ọ̀dàlúrú Ọmọ-Ìta
Ajá Tó Máa Sọnù Kì Í Gbọ́ Fèrè Ọlọ́dẹ Olóṣèlú Nigeria kan, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, Honorable Sanya Omirin, ni ọ̀daràn kan ti dárúkọ rẹ̀ o, gẹ́gẹ́bí ẹni tí ó máa nrán àwọn ní iṣẹ́ ibi, tí ó sì fún àwọn ní ọgbọ̀n ìbọn láti ṣe iṣẹ́ ibi náà. Èyí tí […]