ÌKÓNILẸ́RÚ TIPÁTIPÁ !
Ìròyìn tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ sọ pé ìlú Amẹ́ríkà sọ pé ó tẹ́ òun lọ́rùn kí orílẹ̀-èdè Áfríkà méjì jẹ́ ọmọ-ẹgbẹ́-múléjóko nínú Ìgbìmọ̀ Aláàbò Àjọ Àgbáyé, yàtọ̀ sí bí ó ṣe jẹ́ tẹ́lẹ̀ tí orílẹ̀-èdè aláwọ̀dúdú kankan ò sì nínú ìgbìmọ̀ múléjòkónáà. Ṣùgbọ́n, ọkùnrin aláwọ̀dúdú ọmọ Áfríkà tí ó gbé ìròyìn náà sí’nú fọ́nrán […]