ỌBA ILẸ̀ YORÙBÁ KÍ ÀWỌN AMÚNISÌN TÓ DÉ
Ní ìgbà àtijọ́, àwọn ọba ní olórí ìjọba ní ilẹ̀ Yorùbá, wọ́n nṣe àkóso ìlú ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn ìjòyè wọn. Láti inú irú ìṣàkóso yí ní a tí mú ọ̀rọ̀ “Ìjọba” jáde tí ó túmọ̀ sí àjọ àwọn ọba tàbí ìgbìmọ̀ àwọn ọba. Kí àwọn òyìnbó amúnisìn tó dé, ní ilẹ̀ Yorùbá tí ní […]