ELÉYI MÀ WÁ GA O! ORÍṢIRÍṢI ABURÚ, LÁTÀRÍ ÌWÀ AJẸGÀBA NÀÌJÍRÍÀ
Ẹnikẹ́ni tí ó bá fi ojú àánú wo Nàìjíríà, nígbàtí ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìyà wọn bá dé, irúfẹ́ ẹni bẹ́ẹ̀ nílò àyẹ̀wo! Bí a ti ngbọ́ kan, ni a tún ngbọ́ míì, ní oríṣiríṣi ìṣẹ̀lẹ̀ aburú tó nṣẹlẹ̀ ní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, látàrí pé Nàìjíríà ṣáà fi ipá jẹgàba sí orí ilẹ̀ wa. Láìpẹ́ yí […]