Mẹ́wàá Nṣẹlẹ̀ Nílẹ̀ Yorùba!
Hmmm, nǹkan ń kán, mẹ́wàá ń ṣẹlẹ̀ nílẹ̀ Yorùbá! Àjálù iná tó jó ilé ní Erékùṣù Èkó ní ọdún k’ọ̀la ṣe wá ní kàyéfì. Ṣùgbọ́n àwọn bàbá wa bọ̀, wọ́n wí pé “Bí nǹkan kò ba ṣe ẹ̀sẹ́, ẹ̀sẹ́ kìí déédéé sẹ́. Ṣé Olójú kò ní r’ójú e ni’le, kó sọ pé kó fọ́, àjókòó-dìde […]