Ọmọ Yorùbá, Ẹ Jẹ́ Kí A Kíyèsíara Nípa Òògùn Lílò
Ìròyìn tí a gbọ́ l’orí ayélujára X, èyí tí a mọ̀ sí Twitter tẹ́’lẹ̀, tí ọjọ́ kejìlá oṣù kẹfà ẹgbàá ọdún ó-lé-mérìn-lé-lógún, ni a ti ríi ní’bi tí wọ́n ti ń fi ọ̀rọ̀ wá arákùnrin òyìnbó kan lénu wò, ó wá ń ṣe àlàyé lórí ipa àti àṣeyọrí tí òun àti àwọn ẹlẹ́gbẹ́ rẹ̀ kó […]