Ìkéde pàtàkì fún gbogbo àgbè ní ilè Olómìnira ti YORÙBÁ, lórí èso ogbin tí àwọn òyìnbó bẹ̀rẹ̀ sí ma pín káàkiri ilẹ̀ aláwò dúdú pé ó léwu ooo.

Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí àti àwọn gómìnà Nigeria, tí wọ́n ngbé l’orílẹ̀-èdè Yorùbá, gbogbo ẹ̀ pátápátá l’a nkójọ pọ̀ gẹ́gẹ́bí ẹ̀rí. Share on X

Àlàyé rè ni pé èso tí ó má tún fi dúdú sí abé oko ẹrú òyìnbó tún ní o.

Èso Ọ̀gbìn Aláyé D'èrú - Democratic republic of the yoruba

Àwọn èso yìí máa fi òpin sí oko dídá ni tí ẹ bá ti gbìn ín sí orí ilẹ̀ yín fún ìgbà àkọ́kọ́, ẹ ò ní leè gbìn èso míràn sí orí irú oko náà mó, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ mú pamọ nínú èso náà di ọdún tí ó m bò , àyàfi tí ẹ bá tún dé odo àwọn tí ó ti kókó fún yín gbìn, èyí túmọ̀ sí pé àwọn òyìnbó tún ti mú ipinnu apá’ṣe lórí gbogbo àgbáyé ṣe ní ò, bí ará ìlú aláwò dúdú kò bá dé odò wọn, a kì yóò leè jẹun, a wí fún ní k’ó tó dá ni, àgbà ìjàkadì ní o.

À ń kéde fún àwa ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá (I.Y.P) pé kí á má ṣe gba èso ogbin lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni ooo.