Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌBA ILẸ̀ YORÙBÁ KÍ ÀWỌN AMÚNISÌN TÓ DÉ

Ní ìgbà àtijọ́, àwọn ọba ní olórí ìjọba ní ilẹ̀ Yorùbá, wọ́n nṣe àkóso ìlú ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn ìjòyè wọn. Láti inú irú ìṣàkóso yí ní a tí mú ọ̀rọ̀ “Ìjọba” jáde tí ó túmọ̀ sí àjọ àwọn ọba tàbí ìgbìmọ̀ àwọn ọba. Kí àwọn òyìnbó amúnisìn tó dé, ní ilẹ̀ Yorùbá tí ní […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN Ọ̀TÁ INÚ ILÉ

Àgbà kìí wà lọ́jà k’órí ọmọ tuntun ó wọ́, bí àwọn babańlá wa ṣe máa ń sọ nìyí. Ṣùgbọ́n ní ayé òde òní, àwọn àgbà tó kù s’ọ́jà gan-an orí ti kúrò ní ọrùn wọn ó ti wà ní abẹ́ àtẹ́lẹsẹ̀. Ní ìgbà láéláé tí ìṣẹ̀lẹ̀ kan bá ṣẹlẹ̀ láàárín ìlú, wọ́n á ní kí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

JỌ̀WỌ́ IṢẸ́ SÍLẸ̀ FÚN ALÁKOSO ÈTÒ-ÌṢÚNÁ

Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítiri-Abíọ́lá, ti fi ọ̀rọ̀ ránṣẹ́ sí àwọn gómìnà ìlú-agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà tí wọ́n njẹgàba sorí ilẹ̀ Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), orílẹ̀-èdè wa, pé, lọ́wọ́lọ́wọ́ báyi o, kí wọ́n jọ̀wọ́ iṣẹ́ sílẹ̀ fún àwọn alákoso (DG) ètò-ìṣúná (finance) àti Adájọ́-Àgbà ní gbogbo ìpínlẹ̀ wa (D.R.Y) tí wọ́n gàba lé lórí. Èyí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÀLÀKALẸ̀ ÈTÒ ÌSÈJỌBA D.R.Y

Tí a bá ń sọ̀rọ̀ nípa orílẹ̀ èdè tí Olódùmarè dá lọ́lá ní àgbáyé, ipò Kínní ni orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y) wà nípasẹ̀ àlàkalẹ̀ ètò ìsèjọba tí Olódùmarè gbé fún Màmá wa ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla. Àlàkalẹ̀ yí kún fún orísìírísìí ètò ìgbá’yé-gbádùn, àti pé yóò dá […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ẹ̀JẸ̀ ÀWỌN AMÚNISÌN LÁRA ÀWỌN ỌBA

Látètèkọ́ṣe ti àwọn amúnisìn bẹ̀rẹ̀ láti ma wá s’órílẹ̀ Yorùbá láti bá àwọn Baba nla wa ṣ’edókówò ni àwọn ọmọ Yorùbá ti bẹ̀rẹ̀ sí nbọ́ sínú oko ẹrú lọ́lọ́kan òjọ̀kan. Látì ìgbà yí wá ni wọn mọ̀ dájú wípé ilẹ̀ Yorùbá wà ní ìpele ìjọba kan síkejì tí àwọn amúnisìn si ri dájú pé, àṣẹ […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

NÀÌJÍRÍÀ KÌÍ ṢE ORÍLẸ̀-ÈDÈ

Orílẹ̀-Èdè jẹ́ àwọn ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ènìyàn tí wọ́n jẹ́ ìran kan-náà; èyí tí ó túmọ̀ sí pé, wọ́n ní ORÍSUN kan-náà; èyí sì máa nf’ara hàn nínú pé èdè abínibí kan-náà pa wọ́n pọ̀; bẹ́ẹ̀ ni ìtàn kan-náà pa wọ́n pọ̀, wọ́n sì ní àṣà kan-náà tí ó pà wọ́n pọ̀; bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sábà máa […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÈTÒ ÌDÌBÒ

Ní Orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y), àrà ọ̀tọ̀ ni ètò ìdìbò yóò jẹ́, àwọn ará ìlú ni yóò yan ẹni tí wọ́n fẹ́, bẹ́ẹ̀ ni kò ní sí àyè láti fún ẹnikẹ́ni lówó láti ra ẹ̀rí ọkàn àwọn ará ìlú. Gẹ́gẹ́ bí màmá wa Ìyá Ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ṢÉ Ó YẸ KÍ ÈTÒ ÈNÌYÀN JẸGÀBA SÓRÍ ÌṢẸ̀DÁ OLÓDÙMARÈ?

Ohun tí ó jẹ́ ètò-àtọwọ́dá ọmọ-ènìyàn; ètò àtọwọ́dá àwọn òyìnbó-amunisìn, njẹ́ ètò-àtọwọ́dá ọmọ-ènìyàn yí, ní Ẹ̀tọ́ kankan, níbikíbi ní àgbáyé láti jẹgàba sórí ohun tí Olódùmarè gbé kalẹ̀ nípa ìṣẹ̀dá ọwọ́ rẹ̀? Ẹ jẹ́ kí á tún gbé-e kalẹ̀ ní ọ̀nà míràn. Ṣé ní àìpẹ́ yí ni Màmá Ìran Yorùbá, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, gbe síta […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

Ọ̀RỌ̀ ÒMÙGỌ̀ LẸ́NU Ọ̀BÀYÉJẸ́

“Mò ń bínú sí ara ìlú” Kí ló gbé ọ̀rọ̀ yi jáde láti ẹnu Rotimi Amaechi, ẹni tó ti jẹ gómìnà àti minisita nìgbà kan rí? Bẹni a ń bi ní, nígbà tí àwọn ǹkan kàyèfi bá ń ṣẹlẹ̀. Fọ́nrán kan lari lórí ẹ̀rọ ayélujára, nibẹ ni gómìnà yìí tí ń sọ ọkàn rẹ jáde […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌTỌ́JÚ ÀWỌN ỌMỌDÉ

Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y), kò sí ẹni tí kò ní gbádùn àlàkalẹ̀ ètò ìṣèjọba tí Olódùmarè fún màmá wa, ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla, pàápàá jù lọ àwọn ọmọdé. Ètò ti wà nílẹ̀ lorísìírísìí fún ìgbá’yé gbádùn àwọn ọmọdé. Bí wọ́n bá ti ń gbà ìtọ́jú ni […]

Read more