Ajá T’ó Fẹ́ Sọnù Ni Nàìjíríà!
Bẹ́ẹ̀ ni, ọ̀rọ̀ ajá t’ó fẹ́ sọnù ni ọ̀rọ̀ Nàìjíríà, kò níí gbọ́ fèrè ọdẹ! Òwe Ìkìlọ̀ Yorùbá A tún ti gbọ́ ìròyìn míràn tí ó fi hàn gbangba wípé Nàìjíríà ṣì pàpà nka ilẹ̀ Yorùbá mọ́ ìlú Nàìjíríà, l’ẹhìn ìgbà tí Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá ti di orílẹ̀-èdè aṣe’jọba-ara-ẹni! Èyí ni ó jẹ […]