Ìjọba Agbésùnmọ̀mí Ṣe Òfin Oní’lé-Gbé’lé Ní Èkìti!
Ìpínlẹ̀ Èkìtì jẹ́ ìkan nínú àwọn ìpínlẹ̀ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, l’abẹ́ ìṣ’àkóso Ìjọba Adelé Orílẹ̀-Èdè Yorùbá, pẹ̀lú Mobọ́lájí Ọláwálé Akinọlá Ọmọ́kọrẹ́ tí ó jẹ́ olórí ìjọba adelé orílẹ̀-èdè Yorùbá. Ṣùgbọ́n àwọn ìjọba agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà (ìjọba tẹ́rọ́síìs) tí wọ́n fi ipá dúró l’orí ilẹ̀ wa, ilẹ̀ Yorùbá, tí agbésùnmọ̀mí apàà’yàn Oyèbánjí tí nàìjíríà npè […]