Ọmọ Yorùbá, ẹ la’ti yín silẹ dáadáa…
Ọta ìran ni àwọn ti a ń fojú wọn han yi. Ènìyàn bi ẹranko ni wọn, Kódà ní àwùjọ ẹranko, wọn ko gbọdọ mọ pe mo fi wọn wé àwọn. Nítorí pe, ti a ba wo, iwuwasi ẹranko, a o ri pé wọn l’ọgbọ́n lórí ju àwọn apànìyàn wọnyi.
Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí àti àwọn gómìnà Nigeria, tí wọ́n ngbé l’orílẹ̀-èdè Yorùbá, gbogbo ẹ̀ pátápátá l’a nkójọ pọ̀ gẹ́gẹ́bí ẹ̀rí. Share on XTi ènìyàn ko ba ni ọpọlọ lórí, ṣé bí a maa ni’fẹ ọmọlakeji rẹ; Ò tí ò, bi ti àwọn gómìnà irinṣẹ́ Agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà kọ! Gbogbo òun to ń ṣẹlẹ̀ ni ilẹ̀ Yorùbá lóni ko ṣẹ́yìn àwọn olè wọnyi.
Bi wọn ṣé ń f”ebi p’ara ìlú, bẹẹni wọn nrán àwọn darandaran sínú igbo kí wọn ma p’ara ìlú. Bí wọn ṣé ń wolé naa ni wọn njí ènìyàn gbe.
Ẹ ṣọ́ra fún wọn! Ti adìyẹ yín ba sọnù, ẹ f’oju si wọn lára! Olè ni wọn! Akotile ta, ọmọ àlè ni wọn! Gbogbo òun ti o l’ẹmi ni oògùn òwò àti àgbàrá ni ọdọ wọn.
Ìkìlọ̀ wa rẹ o fún gbogbo ẹyín irinṣẹ́ àti iranṣẹ́ agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà,
Wọn kò sọ fún mi tẹlẹ ko sí nbẹ mọ. Ẹri kàn ni atẹjade tí òní tun jẹ fún gbogbo ẹyin iranṣẹ́ agbèsùnmọ̀mí tí “orílẹ̀ èdè” Nàìjíríà ti ẹ pe ara yín ni gómìnà ti ẹ fí àáké kòrí láti kúrò ní ìjókò to jẹ ti Ọmọ-Aládé Yorùbá ni tòótọ́. Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá ti dúró! Awa o bójú wẹyín mọ.
Orílẹ̀-Èdè Yorùbá Ni Ìlú Osun. Iranṣẹ́ Agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà, Adeleke, Kúrò Ní Secretariat (Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba) Ní ìlú Osogbo! Olè !! Já’de!
Ka Ìròyìn: Ojú Olè Ré: Àwọn Apànìyàn Agbèsùnmọ̀mí Tí Wọ́n Pè rà wọn Ni Gómìnà
Iranṣẹ́ Agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà, Aiyedatiwa, Kúrò Ní Secretariat (Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba) Ní ìlú Ìpínlẹ̀ Òndó. Ọmọ Yorùbá Fẹ́ Lo Nkan Wọn! Yorùbá Kò Sí L’ara Nigeria Mọ́.
Iranṣẹ́ Agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà, Usman Ododo, Kúrò Ní Secretariat (Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba) Ní ìlú Ìpínlẹ̀ Kogi (èyí ti o jẹ apa ti ilẹ̀ Yorùbá). Ọmọ Yorùbá Fẹ́ Lo Nkan Wọn! Yorùbá Kò Sí L’ara Nigeria Mọ́!
Iranṣẹ́ Agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà, abdulrahman Abdulrazaq, Kúrò Ní Secretariat (Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba) Ní Ìpínlè Ọ̀yọ́ Empire, Ọmọ Yorùbá Fẹ́ Lo Nkan Wọn! Yorùbá Kò Sí L’ara Nigeria Mọ́.
Ka Ìròyìn: Ayédatiwa, Kúrò L’orí Àlééfà Ọmọ Yorùbá