Wọn ko sọ fún mi tẹlẹ ko si nbẹ mọ. Ẹri kàn ni atẹjade tí òní tun jẹ fún gbogbo ẹyin iranṣẹ́ agbèsùnmọ̀mí tí “orílẹ̀ èdè” Nàìjíríà ti ẹ pe ara yín ni gómìnà ti ẹ fí àáké kòrí láti kúrò ní ìjókò to jẹ ti Ọmọ-Aládé Yorùbá ni tòótọ́. Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá ti dúró! Awa o bójú wẹyín mọ.
Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí àti àwọn gómìnà Nigeria, tí wọ́n ngbé l’orílẹ̀-èdè Yorùbá, gbogbo ẹ̀ pátápátá l’a nkójọ pọ̀ gẹ́gẹ́bí ẹ̀rí. Share on XIranṣẹ́ Agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà, Sèyí Mákindé, Kúrò Ní Secretariat (Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba) Ní Ìbàdàn! Orílẹ̀-Èdè Yorùbá Ni Ìlú Ìbàdàn! Orílẹ̀-Èdè Yorùbá Ni Ilú Ìbàdan!!
Orílẹ̀-Èdè Yorùbá Ni Ìlú Àti Ìpínlẹ̀ Èko! Iranṣẹ́ Agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà, Sanwó-Olú, Kúrò Ní Secretariat (Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba) Ní Ìkẹjà! Olè !! Já’de!
Iranṣẹ́ Agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà, Adélékè, Kúrò Ní Secretariat (Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba) Ní ìlú Ìpínlẹ̀ Osun. Ọmọ Yorùbá Fẹ́ Lo Nkan Wọn! Yorùbá Kò Sí L’ara Nigeria Mọ́
Iranṣẹ́ Agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà, Oyèbanjí, Kúrò Ní Secretariat (Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba) Ní ìlú Ìpínlẹ̀ Osun. Ọmọ Yorùbá Fẹ́ Lo Nkan Wọn! Yorùbá Kò Sí L’ara Nigeria Mọ́
Iranṣẹ́ Agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà, Dàpọ̀ Abíọ́dún, Kúrò Ní Secretariat (Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba) Ní Òkè Imosàn Abẹ́òkúta Ọmọ Yorùbá Fẹ́ Lo Nkan Wọn! Yorùbá Kò Sí L’ara Nigeria Mọ́
Iranṣẹ́ Agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà, abdulrahman Abdulrazaq, Kúrò Ní Secretariat (Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba) Ní Òkè Imosàn Abẹ́òkúta Ọmọ Yorùbá Fẹ́ Lo Nkan Wọn! Yorùbá Kò Sí L’ara Nigeria Mọ́