Ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (I.Y.P), Ẹ̀ Jẹ́ Kí á Bá’ra Wa Sọrọ
Ní ìkóríta t’a dé yí, ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, ẹ jẹ́ kí á bá ara wa sọ àwọn géndé ọ̀rọ̀ kan. Gbogbo wa, gẹ́gẹ́bí ọmọ rere, ojúl’owó ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, ni a fẹ́ ohun rere fún ìgbádùn ìgbésí ayé wa. Àkókò mélo ni a fẹ́ lò l’ayé, tí a bá ní kí á fi ojú ara […]