Ilé-Ẹjọ́ Tí Ó Gajù Ní Ìlú Tí Ó Fẹ̀gbẹ́ Tì Wá, Dá Awọn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Lẹ́bi Lórí Owó Ìṣúná Fún Àwọn Ìjọba Ìbílẹ̀ Wọn
Ilé-ẹjọ́ tí ó gajù ní agbègbè tí ó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ Orílẹ̀ Èdè wa, Democratic Republic of the Yorùbá, èyí tí nwọ́n npè ní Nàìjíríà, ti fi òpin sí ìwa kí a máa jẹ gàba lórí owó ìṣúná tí ó yẹ láti lọ sí àpò ìjọba tí ó súnmọ́ ará ìlú jùlọ ní orílẹ̀-èdè tiwọn l’ọhún, […]