ÀYÀBÁ ÀTI ÌDANI-L’ORÍ-RÚ (CONFUSION AND DISTRACTION)
Èyí ni l’ati sọ fún Ìjọba agbésùnmọ̀mí Nigeria, àti àwọn ẹmẹ̀wà wọn tó jẹgàba lórí ilẹ̀ Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y) ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, D.R.Y; lára èyí tí a rí Adémọ́lá Adélékè tí ó pera rẹ̀ ní gómìnà, bẹ́ẹ̀ náà ni ẹni tí ó pera rẹ̀ ní Ọ̀gá Ọlọ́pa ní bẹ̀, ṣùgbọ́n tí ó […]