• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

BÍ ÀWỌN ÒYÌNBÓ ALÁWỌ̀ FUNFUN ṢE Ń KÓ ỌRỌ̀ ÀWA ADÚLÁWỌ̀

Bí àwọn òpònú olóṣèlú ní ilẹ̀ adúláwọ̀, pàápàá ní ìlú agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà, ṣe ń ronú oríṣiríṣi ọ̀nà láti jí owó kó sí àpò ara wọn, bẹ́ẹ̀ náà ní àwọn òyìnbó aláwọ̀ funfun ń ronú nígbà gbogbo oríṣiríṣi ọ̀nà tí àwọn ó tún gbà láti leè túbọ̀ máa kó àwọn ohun àlùmọ́ọ́nì wa, síwájú àti síwájú […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀWỌN ỌMỌ ÌBÍLẸ̀ ÈKÓ PE SANWÓ-OLÚ NÍ’JÀ, L’ORÍ ILẸ̀ TÍ DANGOTE NÍ ÒUN SAN ỌGỌ́RUN MÍLÍỌ̀NÙ DỌ́LÀ FÚN

Ọwọ́ tí ọ̀gẹ̀dẹ̀ bá gbé, ara rẹ̀ ló fi ń nà o. Àwọn ẹgbẹ́ kan ní Ìlú Èkó, tí wọ́n pe ara wọn ní “De Renaissance Patriots Foundation,” ti kọ ìwé sí Wèrè-Ìlú-Èkó, Babajídé Sanwó-Olú, gómìnà Nàìjíríà tó fipá jẹgàba ní Ìpínlẹ̀-Èkó ti Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, pé kí ó wá ṣe àlàyé lórí […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀWỌN OÚNJẸ ILẸ̀ YORÙBÁ

Iyán l’oúnjẹ, ọkà l’oògùn, àìrí rárá l’àńjẹ̀kọ, k’ẹ́numádilẹ̀ ni ti gúgúrú. Èyí ń tọ́ka sí bí àwa ìran Yorùbá ti ṣe ní oríṣiríṣi oúnjẹ, kìíwá ṣe oúnjẹ lásán, ṣùgbọ́n àwọn oúnjẹ tí ó ń ṣe àǹfààní ní àgọ́ ara wa. Kìí se àwọn ayédèrú, tàbí èyí tí a gbìn ní ọ̀nà ti ìgbàlódé pẹ̀lú oríṣiríṣi […]

Read more
Iroyin ojojumo ile yoruba nation dry -yoruba nation is not nigeria.

ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TI YORÙBÁ JẸ́ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA AṢÈJỌBA-ARA-ẸNI

Ọwọ́ tí ọ̀gẹ̀dẹ̀ bá gbé, ara rẹ̀ ló fi ń nà o. ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ TI BÁ WA GBA ÌJẸ́-ORÍLẸ̀-ÈDÈ WA PADÀ, NÍ OGÚNJỌ́ OṢÙ BÉLÚ, ẸGBÀÁ ỌDÚN Ó LÉ MÉJÌ-LÉ-L’OGÚN ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ TI BÁ WA GBA ÌṢÈJỌBA-ARA-WA PADÀ NÍ ỌJỌ́ KÉJÌLÁ, OṢÙ IGBE, ẸGBÀÁ ỌDÚN Ó LÉ MẸ́RIN-LÉ-L’OGÚN ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TI YORÚBÁ TI JÁ’DE […]

Read more
Democratic republic of the Yoruba - ominira news update | Yoruba Nation | Newest Nation in Africa, World

ÌLÙ NÀÌJÍRÍÀ TI FI ŃKÀN ṢE ÀWỌN ÈWE

Ohun tí kò ṣẹlẹ̀ rí láti àtayébáyé wá, tí ìwọ́de ìf’ẹ̀hónúhàn ti máa ń ṣẹlẹ̀, inú ilé ni oníkálukú òbí máa ń tọ́jú àwọn ọmọdé sí, wọn kì í jẹ́ kí ọmọdé jáde rárá. Ẹ wò ìwọ́de tí ó ń lọ lọ́wọ́ ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí a ṣe ríi nínú fídíò, níbi tí àwọn […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ṢÍṢE ARA LÓGE NÍ ILẸ̀ YORÙBÁ

Proverb: A ta bàbà, a fowó-o bàbà ra baba A dúpẹ́ lọ́wọ́ Olódùmarè tí ó rán màmá wá MOA, Modupeola Onitiri-Abiola, sì àwa ọmọ Aládé, tí wọ́n wá kó wa padà wá sórí ilẹ̀ àjogúnbá àwọn bàbà ńlá wa. Ní báyìí, ẹ jẹ́ kí a bẹ̀rẹ̀ sí máa gbé àṣà wá lárugẹ o. Ẹyin IYP […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

JAMIU ABÍỌ́LÁ NHU ÌWÀ ỌMỌ ALÈ

A ta bàbà, a fowó-o bàbà ra baba  Ní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, kò sí ojú-ìṣáájú o, bẹ́ẹ̀ ni kò sí kí á f’ọwọ́ ra ẹnikẹ́ni l’orí. Ìròhìn tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ láti orí ẹ̀rọ ayélujára fi hàn gbangba pé ìkan nínú àwọn ọmọ bàbá wa MKO Abíọ́lá, ìyẹn Jamiu Abíọ́lá, tún ti […]

Read more