Ìyàtọ̀ Tí Ó Wà L’aárín June 12 Àti July 7
MKO Abiola: Ìyàtọ̀ Tí Ó Wà L’aárín June 12 Àti July 7 Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá
MKO Abiola: Ìyàtọ̀ Tí Ó Wà L’aárín June 12 Àti July 7 Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá
Ní’gbà tí Olóyè MKO Abíọ́lá kú, ní ọjọ́ kéje, oṣù kéje, ọdún 1998, a mọ̀ wípé wọ́n fun ní tea mu, Susan Rice, òṣ’iṣẹ́ fún ìjọba America sì pẹ̀lú àwọn tí wọn jọ wa ní’bẹ̀, pẹ̀lú àwọn ìjọba ol’ógun Nigeria. Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí àti àwọn gómìnà Nigeria, tí […]
Ní ìkóríta t’a dé yí, ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, ẹ jẹ́ kí á bá ara wa sọ àwọn géndé ọ̀rọ̀ kan. Gbogbo wa, gẹ́gẹ́bí ọmọ rere, ojúl’owó ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, ni a fẹ́ ohun rere fún ìgbádùn ìgbésí ayé wa. Àkókò mélo ni a fẹ́ lò l’ayé, tí a bá ní kí á fi ojú ara […]
Àfi ẹnití kò bá mọ ọṣẹ́ tí àwọn ọmọ Íbò tí ṣe sí àwọn ẹ̀yà míràn ní ibi tí àwọn òyìnbó amúnisìn kó papọ̀ ní’jọ́ náà l’ọhún, tí wọ́n pè ní Nigeria, l’ó máa rò wípé ènìyàn gidi ni àwọn ìran Íbò jẹ́. Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí […]
Orílẹ̀-Èdè Yorùbá jẹ́ Orílẹ̀-Èdè Olómìnira ti ara rẹ̀. Gbogbo ìgbésẹ̀ tí orílẹ̀-èdè Nigerí àti àwọn gómìnà Nigeria, tí wọ́n ngbé l’orílẹ̀-èdè Yorùbá, gbogbo ẹ̀ pátápátá l’a nkójọ pọ̀ gẹ́gẹ́bí ẹ̀rí. Olori Adele Orílẹ̀-Èdè Yorùbá, Ọgbeni Mobọlaji Ọlawale Akinọla Ọmọkore A dúpẹ́ l’ọwọ́ Ọlọ́run Olódùmarè, fún Àánú àti Ààbò Rẹ̀, l’orí gbogbo àwa ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá. […]
Ọ̀pọ̀l’ọpọ̀ ọmọ Yorùbá, l’oní, ni kò mọ̀ wípé, ní ìgbà kan rí, nígbàtí Yorùbá ṣì nṣe àkóso ara wọn bí ó ti’lẹ̀ jẹ́ wípé Nàìjíríyà ṣì mbá ìjọba àpapọ̀ lọ ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ wípé, Yorùbá wà ní àyè ara rẹ̀; nṣe ni ìpèsè omi ẹ̀rọ t’ó mọ́ gaara wà káàkiri ilẹ̀ Yorùbá. Títí dé […]
Ẹnik’ẹni ní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (D.R.Y) tí ó bá fẹ́ gbé àpótí Ìbò nígbàkúgbà, kí ó mọ̀ báyi wípé kò ní ọ̀rọ̀ owó nínú o. Kò sí wípé iye owó bái ni o máa fi gba ìwé pé o ní’fẹ́ àti gbé’gbá ìbò, rárá o! Ẹnik’ẹni tí ó bá sì tìtorí ẹni t’ó […]
Ìránṣẹ́ Ọlọ́run Alààyè sí Àwa Ìran Yorùbá, Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, sọ gbẹgudu ọ̀rọ̀ fún àwọn ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, ti Oríl-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, ní ọjọ́ ‘rú, ọjọ́ kéjìlá, oṣù kẹ́fà, odún 2024, tí ó jẹ́ àyájọ́ ọjọ́ tí Olóògbé MKO Abíọ́lá tí wọ́n já’wé olúborí nínú ìdíje fún ipò ààrẹ ní ìlú Nigeria nígbànáà, ṣùgbọ́n […]
Èyí kìí ṣe ọ̀rọ̀ ìkórira òyìnbó, ṣùgbọn, tí a kò bá ní tan ara wa jẹ, a níl’ati jẹ́ kí a mọ oríṣiríṣi ohun ibi tí àwọn òyìnbó wọ̀nyí nṣe sí ọmọ ènìyàn àti sí gbogbo àyé. Ní àípẹ́ yi ni òṣìṣẹ́ ètò ìwòsan kan tí òun fún’ra rẹ̀ jẹ́ òyìnbó, ni ó sọ, tí […]
Yorùbá jẹ́ Ẹ̀yà àti Ìran tí Ọlọ́run dá pẹ̀lú ọ̀pọ̀l’ọpọ̀ iyì àti ẹ̀yẹ nínú ìṣẹ̀dá wọn. Èyí ni ó fi jẹ́ wípé, ní ibi gbogbo àti ní ìgbàkúgbà, ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ wípé ní gbogbo àgbáyé ni a ti dá ìran Yorùbá mọ̀ gẹ́gẹ́bí ìran t’ó wu’yì l’ọpọ̀l’ọpọ̀! Ọmọ Yorùbá ṣe oge dé’bi wípé àt’ọkùnrin àt’obìnrin […]