Èèmọ̀! Àwọn Ọ̀dọ́ Yorùbá Mbẹ̀bẹ̀ Fún Owó Ní’gboro Èkó
Èèmọ̀! A rí fidíò kan l’orí ìkànnì @Nwaadaz ní orí X (èyí tí a mọ̀ tẹ́’lẹ̀ sí Twitter), ní’bi tí àwọn ọmọ wa, àwọn ọmọ ol’ogo, àwọn ọmọ al’adé, àwọn géndé ọ̀dọ́ Yorùbá ti mbẹ àwọn ènìyàn tí wọ́n nkọjá lọ nínú mọ́tò ti wọn, wípé kí àwọn tí ó nkọjá lọ wọ̀nyí, kí wọ́n […]