ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRATIWANTIWA TI YORÙBÁ: ÌTỌ́JÚ ÀWỌN ỌMỌ OLÓGO
Màmá wa, Olùgbàlà Ìran Yorùbá, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, sọ pé gbogbo ọmọ Yorùbá tí aburú ti dé bá ìgbésí ayé wọn látàrí ìwàk’iwà, ni yíò rí kádàrá wọn gbà padà gẹ́gẹ́bí ọmọ ológo tí Olódùmarè fẹ́ kí wọ́n jẹ́. Ìyá wa sọ pé inkan tó bá máa gbà ni a máa fun, kí ògo wọn […]