Ọ̀RÀN LÓRÍ Ọ̀RÀN..
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀jù-Lẹ̀kkí tí Dangotè, ọmọ Fúlàní ṣe ilé-iṣẹ́ ìfọ’po sí, ní ìlẹ̀ Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), tí ó sì sọ pé òun san ọgọ́run mílíọ̀nù dọ́là fún ẹgbẹ̀rún-méje ékà ilẹ̀ náà, kò tíì kúrò nílẹ̀. A gbọ́ ìròyìn tí ó sọ pé àwọn kan tí wọ́n pe’ra wọn ní “Ibeju-Lekki People’s Forum” ti […]