The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Àwọn Ìkà Èèyàn Fẹ́ Pààrọ̀ Ẹran Dáradára Pẹ̀lú Ẹran Ayédèrú

Ìjọba Orílẹ̀-Èdè Yorùbá ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ní ṣíṣẹ̀ n tẹ̀lé. Àwọn bàbá wa á máa sọ wípé “Ìfura l’òògùn àgbà, páńsá ò fura páásá já síná, àjà ò fura, àjá jìn, onílé tí ò bá fura, olè ni ó ko lọ”. Òwe Yorùbá Gbogbo àwa ọmọ ìbílẹ̀ Yoruba, ẹ jẹ́ kí a máa fura o. […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Àjàkálẹ̀-Àrùn Ún Ṣẹ́ Yọ N’ílùú Ìpínlẹ̀ Èkó, Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa Yorùbá

Èyí ni bí àwon olùgbé ṣe lè dáàbò bo ara wọn: Ó hàn gbangba pé ilé-iṣẹ́ ìwé ìròyìn kan tí orúko rè ńjẹ́ SÀHÁRÀ gbée jáde wípé àrùn kan tí wọ́n ńpè ní ‘Onígbáméjí ṣẹ́ yọ ní Ìlú Èkó, nítorínáà àwa Ọmọ Ìbílẹ̀ẹ Yorùbá níláti tètè kíyèsára. Èyí rí bẹ́ẹ̀ nítorípé ìjọba Orílẹ̀-Èdè Yorùbá Olómìnira […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Bill Gates – Ìránṣẹ́ Apànìyàn Tí Àṣìtáánì Nlo Lati Ṣe’Jàǹbá Fun Aláwọ̀dúdú

Etí ẹ mélo, ọmọ Yorùbá? Tí o kò bá ìtíìgbọ́ tẹ́lẹ̀, ṣíra, báyi, k’óo gbọ́! Arákùnrin òyìnbó kan wà tí orúkọ rẹ̀ njẹ́ Bill Gates. Apànìyàn ni. Ibik’ibi tí o bá ti gbọ́ orúkọ ẹ̀, kí o má ṣe gbàá l’aàyè l’ati ṣe iṣẹ́ ibi ẹ̀. Bill Gates ní ìgbàgbọ́ wípé ọmọ ènìyàn tí ó […]

Read more
Iroyin ojojumo ile yoruba nation dry -yoruba nation is not nigeria.

Ohun Nlá Ṣẹlẹ̀ Nílẹ̀ Yorùbá Ní Ọjọ́ Kéjìlá, Oṣù Kẹ́rin, Ọdún 2024!

Bẹ́ẹ̀ ni! Ohun nlá l’ó ṣẹ’lẹ̀, ní Ọjọ́ Kéjìlá, Oṣù kẹ́rin, èyíinì, Oṣù Ìgbé; ní ọdún 2024 yí (ẹgbàá ọdún, olé mẹ́rin-lé-l’ogún). Ohun tí ó ṣẹ’lẹ̀ ni wípé, ILẸ̀ YORÙBÁ, èyí tí ó jẹ́ wípé, tẹ́’lẹ̀, a mọ̀ọ́ sí àwọn Ìpínlẹ̀ Èkó, Ìpínlẹ̀ Ògùn, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Ìpínlẹ̀ Ondo, Ìpínlẹ̀ Èkìtì; Ìpínlẹ̀ Kwara, àti […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Àwa Ojúlówó Ọmọ Òmìnira Yorùbá Àtàtà Kìí Ṣe Ajìjàgbara Mọ́ Ooo

A Ríkà Nínú Ìwé Ìròyìn Pilot Ti Ọjọ́ Jimo, Ọjọ́ Kẹrìnlá Oṣù Kẹfà Ọdún Ẹgbàá-Ó-Lé-Mẹ́rin-Lé-Lógún Wípé Àwọn Kan Tí Wón Pé Ara Wọn Ní Yorùbá Nation Agitators Gba’ná Jẹ Fún Àwọn Tí  Wọ́n Pe Ara Wọn Ní Gómìnà Ìwọ-Oorun Nigeria Wípé Dandan Ni Kí Àwọn Gba Òmìnira Fún Yorùbá, He Èé!, Yorùbá Èwo Tún Ní?, […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ilẹ̀ Yorùbá, Agbára Ọ̀dọ́

Awọn bàbá wa sọ wípé, Ọmọdé gbọ́n, Àgbà gbọ́n, laafi dá’lẹ̀ Ifẹ̀. Bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n sọ wípé, Ọwọ́ ọmọdé kò tó Pẹpẹ; ṣùgbọ́n, àgbàlagbà tí ọwọ́ rẹ̀ tó pẹpẹ nkọ́? ti ó bá gbé kèrègbè l’ati orí pẹpẹ, à ti mú nkan t’ó wà nínú kèrègbè náà nkọ́? Ọwọ́ àgbàlagbà ti tóbi jù l’ati […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Àwọn Orúkọ Ní’lẹ̀ Yorùbá Tí Ó Ngbé Àwọn Akọni L’arugẹ Tàbí Àṣà Yorùbá

A tún ntẹ̀ síwájú, l’oní, nípa sís’ọ̀rọ̀ nípa àwọn orúkọ ìlẹ̀ Yorùbá. Yàtọ̀ sí orúkọ àmút’ọ̀runwá, a lè sọ ọmọ wa ní oríṣiríṣi orúkọ tí ó bá wù wá. Orúkọ tí a bá fún ọmọ wa, yàtọ̀ sí orúkọ àmút’ọ̀runwá; òun ni a mpè ní ORÚKỌ ÀBÍSỌ. Kì nṣe gbogbo ọmọ ni ó ní orúkọ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Mẹ́wàá Nṣẹlẹ̀ Nílẹ̀ Yorùba!

Hmmm, nǹkan ń kán, mẹ́wàá ń ṣẹlẹ̀ nílẹ̀ Yorùbá! Àjálù iná tó jó ilé ní Erékùṣù Èkó ní ọdún k’ọ̀la ṣe wá ní kàyéfì. Ṣùgbọ́n àwọn bàbá wa bọ̀, wọ́n wí pé “Bí nǹkan kò ba ṣe ẹ̀sẹ́, ẹ̀sẹ́ kìí déédéé sẹ́. Ṣé Olójú kò ní r’ójú e ni’le, kó sọ pé kó fọ́, àjókòó-dìde […]

Read more