A NÍ L’ATI ṢỌ́’RA GIDI FÚN OYÍNBÓ
Ó ti wá d’ojú ẹ̀, pátápátá báyi o, Ọmọ Yorùbá, ṣé ẹ mọ̀ wípé a ti ní ìjọba tiwa ní ìsinìyí, a sì ní l’ati bo’jú tó ara wa, gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀-èdè. Àwa ni a fẹ́ òmìnira o, a sì ti ri. Ní òtítọ́ àti ní òdodo, àgbékalẹ̀ (èyíinì, àlàkalẹ̀, tabí BluePrint) fún Orílẹ̀-Èdè Olómìnira […]