The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ẹ JẸ́ KÍ Á FURA

Ẹni tí kò bá mọ̀ tẹ́lẹ̀, kí ó yára mọ̀ báyi – àwọn òyìnbó amúnisìn fẹ́ pa áfríkà run ni, kí àwọn lè wá jóko sí orí-ilẹ̀ wa, nítorí ilẹ̀ wa ni oríṣiríṣi ohun-àmúṣọrọ̀ wà (resources). Òyìnbò ò kì nṣe ọ̀rẹ́ aláwọ̀dúdú, ìyẹn ni kí a jẹ́ kí ó yé wa, dáradára.  Nítorí náà, ẹ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ILẸ̀ FÚN ÀWỌN ỌMỌ WA

Oore ńlá tí ìran Yorùbá kò ní gbàgbé láéláé ní Olódùmarè ṣe fún wa nípasẹ̀ màmá wa Modúpẹ́ọlá Onítìrí-Abíọ́lá (Olóyè Ìyá Ààfin) tí  Olódùmarè lò láti gbà wá kúrò lóko ẹrú, pẹ̀lú àlàkalẹ̀ ètò ìṣàkóso tí yóò mú kí gbogbo àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People I.Y.P) ti orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀṢÍRÍ ÌPÀDÉ ÀWỌN ỌLỌ̀TẸ̀ TÚ

Nígbà àjoyọ̀ àjọ̀dún ọdún kejì ìfitónilétí gbígba ohun ìní wá padà, tí a ṣe ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Ọ̀pẹ ẹgbàá ọdún ó lé mẹ́rìnlélógún ni màmá wa Modúpẹ́ọlá Onítìrí-Abíọ́lá (Olóyè Ìyá Ààfin) tú àṣírí ìpàdé ọ̀tẹ̀ tí àwọn ọmọ àlè Yorùbá kan ń ṣe láti dojú ìjà kọ Orílẹ̀ Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: A Ò NÍ SỌ ÌDÁNIMỌ̀ WA NÙ

Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y) a ò ní sọ ìdánimọ̀ wa nù nítorí pé odò tí ó bá gbàgbé orísun rẹ̀, yóò gbẹ ni. Gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí màmá wa Modúpẹ́ọlá Onítìrí-Abíọ́lá (Olóyè Ìyá Ààfin) sọ wípé, èdè Yorùbá nìkan ni a óò máa sọ ní orílẹ̀ èdè […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÈRÒNGBÀ ÀWỌN Ọ̀TÁ INÚ ILÉ

Lára ìkìlọ̀ tí Olódùmarè kọ́kọ́ gbé fún Màmá wa Modúpẹ́ọlá Onítìrí-Abíọ́lá (Olóyè Ìyá-Ààfin) ni láti kíyèsára fún àwọn ọ̀tá inú ilé, pàápàá àwọn ọ̀dọ́ ilẹ̀ Yorùbá láti má jẹ kí ẹnikẹ́ni lò wọ́n láti jẹ́ alátakò àti ọ̀dàlẹ̀ sí ìran Yorùbá. Nitorí, nínú ìdúróṣinṣin wọn ni àìmọye àǹfààní wà. Lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà ni, àwọn ọ̀tá ìta […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÀWỌN OHUN ÀJOGÚNBÁ WA

Oríṣiríṣi nkan ni a jogún bá ní ọwọ́ àwọn bàbá nlá wa, tí Olódùmarè fi kẹ́ ìran Yorùbà láti lè máa gbé ìgbé ayé ìrọ̀rùn àti èyí tí ó ní ògo.  Ọ̀pọ̀lọpọ̀ nkan tí ọwọ́ nṣe, gẹ́gẹ́bí àpẹrẹ, ògiri tí ó jẹ́ ọgọ́run ibùsọ̀ máìlì (èyí tí ó ju ọgọ́run ibùsọ̀ kìlómítà lọ), tí ó […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ọ̀RỌ̀ IKÚ ÀWỌN ỌMỌDÉ TÓ ṢẸLẸ̀

Ọjọ́-burúkú, àṣìtáánì gbomimu, gẹ́gẹ́bí a ṣe máa ngbọ́, ni a lè fi ṣàkàwé ọjọ́ náà, Ọjọ́’Rú, ọjọ́ kéjìdínlógún, oṣù ọ̀pẹ, ẹgbàá-ọdún ó lé mẹ́rinlélógún. Ṣùgbọ́n ní tiwa, ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P) ti Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), ọjọ́ tí Èdùmàrè dá ni-ì, àṣìtáánì kàn ngbógun ni-ì, kò leè borí wa. Gbogbo […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: I.Y.P LE GBÉ IBI TÍ Ó BÁ WÙÚ NÍ D.R.Y

Ọ̀kan lára àwọn àǹfààní tí a ní, ní Orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y) ni pé ibi tó bá wu oníkálukú ló le gbé ní ilẹ̀ Yorùbá. Gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí màmá wa Modupẹọla Onitiri-Abiọla (Olóyè Ìyá-Ààfin) bá àwa ojúlówó ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá sọ láìpẹ́ yí wípé, ọ̀kan ni […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ẸNI TÓ GBA ÌLÚ LÓ Ń ṢE ÌLÚ

Ẹní m’ojú ògún níí p’abì ní’rè. Láìpẹ́ yìí tí màmá wa Modúpẹ́ọlá Onítìrí-Abíọ́lá (Olóyè Ìyá-Ààfin) bá àwa ojúlówó ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yorùbá People, I.Y.P) ti Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y)  sọ̀rọ̀, wọ́n sọ nípa àwọn kan tí wọ́n ń lérí, tí wọ́n ń sọ ìsọkúsọ pé àṣẹ wo ni màmá wa MOA ní, […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀWỌN Ọ̀DARÀN ẸLẸ́SÌN

Kò sí mi ò mọ̀, lábẹ́ òfin. Àwọn kan ti ṣe àkọlù sí ìṣàkóso-ara-ẹni Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y), ó sì di dandan pé ohun tí òfin tí ìṣàkóso-ara-ẹni D.R.Y dúró lé lórí, máa fi han àwọn ọ̀daràn wọ̀nyí, pé ọ̀daràn ni wọ́n, ohun tí ojú wọn bá sì […]

Read more