W.H.O NI ÀRÙN TÓ NJÀ’WA NÍ ÁFRÍKÀ!
Àṣírí ti wá tú pátápátá báyi o! À ṣé àjọ tí ó sọ pé àwọn ń mojútó ètò ìlera ní àgbáyé (W.H.O), ni àjàkálẹ̀ àrùn tí ó njà wá ní Áfríkà báyi! Ẹ gbọ́, kí a tún tún-un gbọ́, àwọn onímọ̀ ìwòsàn kan ní Áfríkà ti sọ fún ààrẹ Museveni ti ìlú Uganda pé, a […]