Àǹfààní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa Ti Yorùbá: Ojúse Ìjọba Fún Àwọn Ara Ìlú
Ní orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y), gbogbo ojúṣe tó yẹ kí àwọn ìjọba ṣe ni wọ́n yóò máa ṣe, tí wọ́n kò sì ní yọ ọ̀kan sílẹ̀ nítorí pé, ìjọba wa yóò nífẹ̀ẹ́ àwọn ará ìlú bẹ́ẹ̀ni wọn kò ní jẹ́ kí ìyà jẹ ẹnikẹ́ni tàbí tẹ ẹ̀tọ́ […]