ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ, ÀWÁMÁRIDÍ, NÍSIÌYÍ, BA GBOGBO OHUN-IBI JẸ́, PÁTÁPÁTÁ; GBOGBO MÁJẸ̀MÚ ÌRÁNṢẸ́-ẸNI-IBI, ÀṢÌTÁÁNÌ, GBOGBO ÌLÉRÍ, ÈTÒ, ÈTE, ÀTI ÈRÒ TÍ Ó LÒDÌ SÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ YORÙBÁ, ÌRAN YORÙBÁ, ILẸ̀ YORÙBÁ, ÌṢÈJỌBA YORÙBÁ, AGBÈGBÈ-ÀJOGÚNBÁ YORÙBÁ. NÍ AGBÁRA TÍ ỌLỌ́RUN FI NJẸ́ ÈMI-NI, KÍ ÌPARUN NÁÀ ṢẸLẸ̀ SÍ ÀWỌN Ọ̀TÁ YORÙBÁ WỌ̀NYÍ, LỌ́WỌ́LỌ́WỌ́ BÁYI
OLÓDÙMARÈ, ALÁGBÁRA, TÍ Ó NÍ IPÁ; OLÓDÙMARÈ TÍ Ó NÍ IPÁ LÓJÚ OGUN, ỌLỌ́RUN ÀWỌN ỌMỌ-OGUN, ṢE ÌPARUN PÁTÁPÁTÁ, NÍSIÌYÍ, FÚN ÀṢẸ, AGBÁRA ÀTI IPÒ TÍ WỌ́N NLÒ LÁTI JẸGÀBA LÓRÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TI YORÙBÁ, ÌRAN YORÙBÁ, ILẸ̀ YORÙBÁ, ÌṢÈJỌBA YORÙBÁ, AGBÈGBÈ-ÀJOGÚNBÁ YORÙBÁ.
ṢE ÌPARUN FÚN GBOGBO ÌWÀ ÌDÚKOKÒ, ÌJẸGÀBA, DÍDẸ́RÙBANI, ÌHÀLẸ̀, ÌGBÓGUN-TINI, TÍ WỌ́N DOJÚKỌ ỌMỌ-ÌBÍLẸ̀-YORÙBÁ, TI ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TI YORÙBÁ
Ẹni tí ó bá sọ pé òun ò ní ìfẹ́ sí òmìnira tí ilẹ̀ Yorùbá ti gbà kúrò nínú Nàìjíríà, tàbí pé òun ò f’ara mọ́ jíjẹ́ orílẹ̀-èdè aṣèjọba-ara-ẹni tí Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) jẹ́, láti ọjọ́ kéjìlá, oṣù igbe, ẹgbàá ọdún ó lé mẹ́rinlélógún, tàbí tí ó lòdì sí ìṣèjọba D.R.Y, l’akókò yí, àti títí láíláí, irúfẹ́ ẹni bẹ́ẹ̀ yẹ fún ẹ̀sùn ìpànìyàn ní ilé-ẹjọ́ D.R.Y.
Ìjọba Nàìjíríà kò ní ṣe rere, bẹ́ẹ̀ ni ònilẹ̀ Yorùbá, láyé, kò ní fi ojú rere wo ohunkóhun tí ó bá jẹ́ ti Nàìjíríà, gbogbo ẹni t’ó bá dẹ̀ fẹ́ gbé ìrònú Nàìjíríà wọ orílẹ̀-èdè D.R.Y, wọ́n yẹ fún ikú.
A ti ngbọ́ l’oríṣiríṣi, a dẹ̀ tún wá fi ojú wa ri: ní ìlú Ọbátẹ̀dó, agbègbè Ìgbátòrò-Jẹ́milúgbà, Ìpínlẹ̀ Ondó, Democratic Republic of the Yoruba; obìnrin kan nbọ̀ láti oko, ó npadà lọ sí ilé; ó kó ẹrù dání – onjẹ, aṣọ, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ; ó sì pe ọlọ́kadà l’ati gbé òun.
Àwọn méjèèjì wà l’orí ọ̀kadà, wọ́n nlọ; inú ọlọ́kadà ndùn pé ajé nwọlé, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìlú le kokoko látàrí ìjẹgàba aṣiwèrè Nàìjíríà lórí ilẹ̀ Yoruba; inú arábìrin wa yí ndùn, pé, bí ó ti le kokoko tó yí, òun ṣì rí nkan mú lọ sí’lé; àwọn ará ilé pàápàá nretíi pé màmá ò ní pẹ́ dé, ẹ̀gbọ́n wa ò ní pẹ́ dé, àbúrò mi ò ní pẹ́ dé: Olódùmarè, nìkan, l’ó mọ iye ẹni tí dídé arábìrin ọ̀ún máa jẹ́ ànfààní tààrà àti ayọ̀ fún; àwọn aládugbò nkọ́? àwọn ìbátan, ní’lé, l’oko, l’ẹyìn-odi.
Oníkálúkú nretíi “màmá káàbọ̀, ọmọ-kúulé.” Ṣùgbọ́n àwọn ẹ̀dá kan wà, l’orí ilẹ̀ ayé yí, wọn ò ní nkan tó njẹ́ ẹ̀jẹ̀ ọmọ-ènìyàn lára; Fúlàní ni a mọ̀ wọ́n sí; àwọn t’ó dẹ̀ rán wọn níṣẹ́, àwọn ọ̀gá wọn, Nàìjíríà ni, ìlú tí ó jẹ́ pé àwọn apànìyàn Fúlàní l’ó ndarí rẹ̀, bẹ́ẹ̀ kẹ̀ dẹ̀ ré, àwọn òyìnbó amúnisìn ni ó ndarí Nàìjíríà.
Àti òyìnbó amúnisìn, àti agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà, àti Fúlàní daran-daran, gbogbo wọn, ọ̀tá ìran Yorùbá, ẹni tí ó bá sì jẹ́ ọ̀tá ìran wa, ẹnikẹ́ni tí ó bá fi ojú àánú wo irúfẹ́ ẹni bẹ́ẹ̀, òun fún’ra rẹ̀ jẹ̀bi ẹ̀sùn ìpànìyàn, ẹnikẹ́ni tí ìbáà wù kó jẹ́ l’orí ilẹ̀ ayé yí!
Àwọn aṣiwèrè, ẹranko l’asán-làsàn, apànìyàn daran-daran Fúlàní wọ̀nyí, yọ sí arábìrin wa yí, ní ilú Ọbátẹ̀dó, agbegbè Ìgbátòrò-Jẹ́milúgbà, Ìpínlẹ̀ Ondó, Democratic Republic of the Yoruba, wọ́n sì yìnbọn sí wọn! Lórí ilẹ̀ Yorùbá! Fúlàní darandaran yìnbọn sí ọmọ ènìyàn méjì, ní orí-ilẹ̀ Yorùbá! Lọ́gán ní obirin náà kú! Ọlọ́kadà, bóyá ó máa yè, à nwojú ọba òkè, wọ́n ṣáà ti gbe lọ sí ilé-ìwòsàn.
Ìròyìn náà kò jù yí lọ; ṣùgbọ́n ohun tí ó wà l’ẹyìn ìròyìn yí, kò ní tán nlẹ – bẹ̀rẹ̀ láti orí àwọn tó pera wọn ní Yorùbá, ṣùgbọ́n tí inú mbí wọn sí òmìnira ilẹ̀ Yorùbá tí a ti gbà láti ogúnjọ́ oṣù bélú, ẹgbàá ọdún ó lé méjìlélógún. Gbogbo ẹ̀yin tí inú mbí, ara l’ó máa ni yín pa!
Olódùmarè á bẹ ẹ̀ṣẹ̀ yín wò lára yín – ẹ̀ṣẹ̀ ìkórira tí ẹ ní sí Ilẹ̀ Yorùbá, Ìran Yorùbá, àti ọmọ Yorùbá. Gbogbo ẹ̀yin tí ó jẹ́ pé ìlú agbésùnmọ̀mí nàìjíríà ni ẹ ní ìfẹ́ sí, kí ilẹ̀ Yorùbá ó bẹ̀rẹ̀ sí takò yín, lọ́wọ́lọ́wọ́ báyi, àti títí láíláí.
Nàìjíríà fún’ra rẹ̀, òpin rẹ ti dé! Àṣemọ fún ẹ, nìyí! O ò ní ri ṣe mọ́, láí! Tinubú, ìwọ wèrè tí Àṣìtáánì gbé sí agbada nàìjíríà, ìlú agbésùnmọ̀mí tí àwa Yorubá àti ilẹ̀ Yorùbá ti kúrò nínú rẹ̀, gbogbo agbára rẹ bàjẹ́ l’oní. Bẹ̀rẹ̀ síí kú, kí o ṣègbé; o ò ní agbára ju Olódùmarè lọ; o ò ṣe rere mọ́ láti òní lọ; a gba èémí imú rẹ lọ́wọ́ rẹ; a gé ahọ́n rẹ, o ò fọ’hùn mọ́ láí! Ayé kẹ̀yìn sí ọ, ọ̀run kọ̀ ọ́ sílẹ̀. A fa ìjọba rẹ ya l’oní, o ṣègbé, kò sì sí àtúnṣe mọ́.
Nàìjíríà, a tú gbogbo ọmọ-ogun rẹ ká, l’oní. Gbogbo ohun tí o fi nṣe agbára; gbogbo ohun tí o fi nhùwà ìjẹgàba s’orí ilẹ̀ Yorùbá, a ja kúrò lára rẹ; gbogbo ibi tí o ti níyì dé tẹ́lẹ̀ rí ní àgbáyé yí, bẹ̀rẹ̀ sí tẹ́. Kí àwọn alátìl’ẹyìn rẹ kí wọ́n sá fún ọ.
Gbogbo ẹ̀yin ọmọ Yorùbá tí ẹ gbàbọ̀dè Fúlàní fún ọmọ Yorùbá, a rán-an yín ní’ṣẹ́ àrèmabọ̀; ẹ ṣègbé, ẹ parun.
Gbogbo Ìran Fúlàní, tiyín ti tán ní ilẹ̀ Yorùbá