Ọmọbìnrin kan tí a rí fídíò rẹ lórí ayélujára X, ló sì fẹ́ má hùwà òpè nípa kí ká Yorùbá mọ Nàìjíríà.
Èyí jẹ́ ìwà òpè gbáà tí ọmọbìnrin nà hù, nítorí Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y) kò sì lára Nàìjíríà mọ láti ìgbà tí ati ṣe ìkéde òmìnira wa, ni ogúnjọ́ oṣù Bélú, ẹgbàá ọdún ó lè méjìlélógún.
Ọ̀kẹ́rẹ́ gungi ìrókò, ojú ọdẹ dá.
Pẹlu ore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run Olódùmarè nípasẹ̀ màmá wá, Ìyà Ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla a ti ṣe ìbúra wọlé fún Olórí Ìjọba Adelé wá, bàbà wa Mobọlaji Ọlawale Akinọla Ọmọkọrẹ, ni ọjọ́ kejìlá oṣù Igbe, ẹgbàá ọdún ó lé mérìnlélógún. Tí iṣẹ́ sì ti bẹ̀rẹ̀ ni pẹrẹu.
Ki obìnrin yíì ṣọ́ ẹnu rẹ̀, kó yẹ hù ìwà òpè mọ. Kó má ka àwa ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá mọ́ ọmọ ìlú ariremáse Nàìjíríà mọ́.
lmura fún ayẹyẹ àjọyọ̀ ló kàn báyìí. Gbogbo àwa Indigenous Yoruba People (I.Y.P.) gbudọ má gbàrà dì fún ọjọ́ ológo ńlá náà. Èyí tí yóò wá yé ni gbogbo Ìpínlẹ̀ méjèèje ni orílẹ̀ èdè wa, Democratic Republic of the Yorùbá (D.R.Y).
Awa ọmọ aládé dúpẹ́ lọ́wọ́ màmá Modupeọla Onitiri-Abiọla tó bá wá ṣe àṣeyọrí ìtusilẹ náà, a mọ̀ ọ̀ lore ó. ̀