Ọgbẹ́ni Mobọlaji Ọlawale Akinọla Ọmọ́kọrẹ́ ni olórí ìjọba Adelé wá (Head of Provisional Government).
Ní Orílẹ̀ Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá ni Olódùmarè ti lo màmá wa, Olóyè Ìyá Ààfin Modúpẹ́ọlá Onitiri-Abiọla láti gba wa kúrò nínú ìgbèkùn àsopọ̀ pẹ̀lù agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà ní ogúnjọ́ oṣù Bélú ẹgbẹ̀wá-ọdún-ó-lé-méjìlelogun, tí ìṣèjọba wa sì bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ Kejìlá oṣù Igbe ẹgbàá ọdún o le mẹrinlelogun nígbàtí a búra wọlé fún olórí ìjọba Adelé wá, bàbá wa Mobọlaji Ọlawale Akinọla Ọmọ́kọrẹ́