• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀMERICA TI F’ỌWỌ́ SÍ ỌSIN ADÌẸ LÁTI YÀRÁ ILÉ Ẹ̀KỌ́ ÌMỌ̀ ÌJÌNLẸ̀

Kò sí àní àní pé Bill Gates lo ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ilé ìtajà ìgbàlódé ńlá ńlá tí wọ́n ti ń ta àwọn awúrúju adìẹ káàkiri àgbáyé. A ríi èyí kà nínú ìròyìn kan lórí ayélujára X, wípé Amerika ti f’ọwọ́ sí ṣíṣe adìẹ àtọwọ́dá láti yàrá ilé ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ìjìnlẹ̀.  Èrèdí èyí ni pé, wọn […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ẸGBẸ̀RÚN MÁRUN NÁÍRÀ NI ÀWỌN ARÁ ÌLÚ NÀÌJÍRÍÀ FI DA’LẸ̀ ARA WỌN !

A rí i lójú, a mọ̀ ọ́ lẹ́nu; òṣòwò oṣẹ kì í pọ́n-wọ́-lá  Ṣé kò kúkú sí ànfààní kankan nínú ìlú wọn ọ̀ún tẹ́lẹ̀ – ìlú t’ó f’ẹ̀gbẹ́ tì wá, Nàìjíríà. Nṣe ni a tún wá gbọ́ báyi, pé, nínú ìfẹ̀hónú-hàn tí wọ́n ní àwọn ọ̀dọ́ wọn nṣe, látàrí bí ìgbé-ayé wọn ṣe le koko […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÒFÉGÈ ÌRÀNLỌ́WỌ́: ọmọ Yorùbá, máṣe yà sí’bẹ̀ !

 PROVERB:  Tinú ọ̀lẹ lọ̀lẹ ńjẹ; aṣiwèrè èèyàn ni ò mọ èrú tí yó gbà Àì fẹ́ẹ́ kúrò lórí ìjẹgàba, èyí tí nàìjíríà njẹgàba ní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, òun ni okùn’fà oríṣiríṣi ìgbésẹ̀ tí Nàìjíríà àti àwọn gómìnà ajẹgàba wọn ní ilẹ̀ Yorùbá ngbé, látàrí kí ọmọ Yorùbá le rò wípé inkan ti bẹ̀rẹ̀ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ỌMỌKÙNRIN KAN ṢE’KÚ PA BÀBÁ TÓ BÍ BÀBÁ RẸ̀ NÍTORÍ OKO

Aò ní ríbi nílẹ̀ yí, ó d’òkèèrè! Ọ̀rọ̀ kò rí bẹ́ẹ̀ ni ìlú Ìlarè-Ìjẹ̀ṣà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun o, níbi tí ọmọkùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Kusibẹ ti ṣe’kú pa bàbá-bàbá rẹ̀ látàrí èmi ni mo ni oko, rárá ìwọ kọ́, ti tèmi ni. Bàbá àgbà, ẹni ọdún méjìdínlọ́gọ́rin, ni a gbọ́ wípé, Kusibẹ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ỌLỌ́PA NÀÌJÍRÍÀ SỌ ARA WỌN DI AMÚNIL’ẸRÚ

Tinú ọ̀lẹ lọ̀lẹ ńjẹ; aṣiwèrè èèyàn ni ò mọ èrú tí yó gbà  Ìròhìn tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́, pẹ̀lú fọ́nrán rẹ̀ fi yé wa wípé ní Lekki, ní Ìpínlẹ̀ Èkó, Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, nṣe ni àwọn ọlọ́pa ìlú Nàijíríà wà ní’bẹ̀ ní rẹpẹtẹ, bí ẹni pé ojú ogun ni! Àti oríṣiríṣi ọkọ̀ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

GBOGBO ỌMỌ YORÙBÁ TÍ Ó JÁDE FÚN ÌFẸ̀HÓNÚHÀN ÌLÚ NÀÌJÍRÍÀ, Ẹ TI DÁ Ọ̀RÀN LÁBẸ́ ÒFIN ORÍLẸ̀-ÈDÈ YORÙBÁ !

Tinú ọ̀lẹ lọ̀lẹ ńjẹ; aṣiwèrè èèyàn ni ò mọ èrú tí yó gbà  Ẹni a wí fún ọba jẹ́ ó gbọ́! Bẹ́ẹ̀ náà ni kò sí àwíjare kankan nílé ẹjọ́ látàrí “mi ò mọ̀ níì..” Ìkéde tí ó jáde láti ọ̀dọ̀ àwọn aṣojú Ojúlówó Ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá, ní àná, ọjọ́ kíní, oṣù ògún, ẹgbàá ọdún […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Japa: Láti Gba Físà Lọ Sí Dubai, Àwọn Ará Naijiria Nilo Ẹgbẹ̀rún Mẹwa Owó Dola Nínú Bánkì Wọn Pẹ̀lú Òjìlélẹ́gbẹ̀ta Ẹgbẹ̀rún Naira Gẹ́gẹ́bí Owó Fọ́ọ̀mù

United Arab Emirates (UAE) àti ìlú agbèsùnmọ̀mí Naijiria parí àríyànjiyàn tí ó wa láàrín wọn gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Mohammed Idris tí ó jẹ́ mínísítà wọn fún ìròhìn ati àlàyé ti sọ síta ní ọjọ́ Ajé pé àwọn tí fí ẹnu kò lórí bí àwọn ará Naijiria yíò tí máa rin ìrìnàjò lọ sí UAE. […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Naijiria Tí Sọ Àwọn Ọ̀dọ́ Ilẹ̀ Yorùbá Di Arúfin Tàn

Ìròhìn tó gbenu tán kan la rí lórí fọ̀rán kan nípa ọ̀dọ́ tó lo ọgbọ́n àrékérekè láti kó owó ninu àpò ilé ìfowópamọ́ bàbá kan ni nílùú Gbẹ̀rígbẹ̀, Ìkòròdú, ìpínlẹ̀ Èkó, ní orílẹ-èdè D.R.Y. Gẹ́gẹ́bí ìròhìn náà, ọ̀dọ́mọkùnrin náà lọ bá bàbá kan pé kí ó jẹ́ kí òun ba ṣáàjì ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ rẹ̀, bàbà […]

Read more