ÀWỌN ÀGBÀ ÒFÒ SỌ Ọ̀RỌ̀ ÀDÁNÙ
Ó ṣeni láàánú pé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni wọ́n pe’ra wọn ní àgbà ṣùgbọ́n ọpọlọ kọ́bọ̀ kò sí lórí wọn. Ní orí ẹ̀rọ Ayélujára ni a ti rí fọ́nrán kan níbi tí àwọn kan tí wọ́n pe ara wọn ní Yorùbá, tí wọ́n tún sọ pé àgbà ni àwọn, tí wọ́n nsọ̀rọ̀ aríremáse nàìjírà bíi pé Orílẹ̀-Èdè […]