ṢEYI MAKINDE ALÉTÍLÁPÁ
Ṣèyí Makinde aláìmọ èyí tó kàn ṣáà ń dá ọ̀ràn kún ọ̀ràn, bẹ́ẹ̀ ló ṣì ń tan àwọn ará ìlú pé òun sì ni gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, ṣé ajá tí yóò sọnù kìí gbọ́ fèrè ọdẹ. Ìròyìn tó tún tẹ̀ wá lọ́wọ́ ni pé, Seyi Makinde fún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba kan ní ìgbéga lẹ́nu iṣẹ́, […]