Ó TI TÁN, PÁTÁ, FÚN ÌRAN FÚLÀNÍ, NÍ ILẸ̀ YORÙBÁ
Ẹni tí ó bá sọ pé òun ò ní ìfẹ́ sí òmìnira tí ilẹ̀ Yorùbá ti gbà kúrò nínú Nàìjíríà, tàbí pé òun ò f’ara mọ́ jíjẹ́ orílẹ̀-èdè aṣèjọba-ara-ẹni tí Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y) jẹ́, láti ọjọ́ kéjìlá, oṣù igbe, ẹgbàá ọdún ó lé mẹ́rinlélógún, tàbí tí ó […]