• Oríkò Ilé-Iṣẹ́, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÈÈMỌ̀ WỌ̀LÚ NÀÌJÍRÍÀ! ÀWỌN Ọ̀DỌ́MỌBÌNRIN ŃTA ẸYIN INÚ WỌN LÁTI RA IRUN ÒYÌNBÓ NÍTORÍ OGE.

Ọ̀dọ́mọbìnrin kan ti ké gbàjarè lórí ẹ̀rọ ayélujára nípa ìwà búburú ọwọ́ àwọn obìnrin ọ̀dọ́ ní ìlú Warri, ìpínlẹ̀ Delta ní ìlú agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà tó fi ẹ̀gbẹ́ tì wá. Lórí fọ́nrán náà, ó wípé ṣe ni wọ́n lọ ńta ẹyin tí ó yẹ kí wọ́n fí bímọ tí wọ́n sì ńfi owó rẹ̀ ra irun […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀJÀKÁLẸ̀ ÀRÙN MPOX: OLÓRÍ ÀJỌ ÌWÒSÀN ÀGBÁYÉ SỌ̀RỌ̀ SÍTA

Olórí Àjọ Ìwòsan ní Àgbáyé ti sọ̀rọ̀ síta nípa àjàkálẹ̀ ààrùn mpox, èyí tí wọ́n sọ pé ó ti ntàn síta kọjá orílẹ̀-èdè Congo, tí wọ́n dẹ̀ nrò pé bóyá ó túbọ̀ lè máa tàn káàkiri Áfríkà àti kọjá Áfríkà pàápàá. Ó ní òun ti pinnu láti gbé ìgbìmọ̀ kan dìde tí ó máa gba […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ LÓRÍ Ọ̀RỌ̀ ÌLÚ GẸ̀Ẹ́SÌ: ỌMỌ YORÙBÁ, Ẹ MÁA BỌ̀ N’LÉ

Ṣébí ní àìpẹ́ yi ni a rí bí àwọn ọ̀dọ́ ìlú Gẹ̀ẹ́si ṣe sọ pé àwọn nfẹ́ ìlú wọn padà, àtí pé àwọn àjèjì ti gba ìlú àwọn mọ́ wọn lọ́wọ́. Ọ̀rọ̀ ré o, àwa Ọmọ Yorùbá; ṣebí ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ìgbà ni Màmá wa, Ìránṣẹ́ Olódùmarè, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí Abíọ́lá, ti máa nsọ fún wa pé, […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÌLÚ APANILẸ́KÚN J’AYÉ NÍ ÌLÚ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍÀ

Gẹ́gẹ́ bí a ti ṣe gbọ́ọ nínú ìròyìn kan pé, àwọn ènìyàn tí ó ní àìsàn ìtọ̀ ṣúgá ni ìlú agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà, ni wọ́n ti pariwo síta o, pé, àwọn oògùn tí àwọn ńlò fún ìtọ́jú ara wọn, èyí tí wọ́n ń rà ní ọ̀kẹ́ mẹ́ta àbọ̀ owó wọn, náírà, tẹ́lẹ̀ ti di ọ̀kẹ́ mẹ́sàn […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀYÍPADÀ Ẹ̀KỌ ́NÍ ORILẸ-EDE OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TI YORÙBÁ 

Orílẹ̀-èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yoruba ní ìlànà fún ètò ẹ̀kọ́ tuntun tí yíò jẹ́ àrà ọ̀tọ̀. Ètò ẹ̀kọ́ tó fọkàn sí ọgbọ́n àti ìmọ̀ tó wúlò fún ayé òde òní.  Ètò yìí yàtọ̀ sí àwọn ètò àtijọ́ tí ó wà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ibi ní àgbáyé. Gẹ́gẹ́bí ìròhìn kan tí a rí lórí ẹ̀rọ ayélujára […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

AṢỌ WÍWỌ̀ NÍ ILẸ̀ YORÙBÁ

Ìrínisí ni ìsọni lọ̀jọ̀, bí a ti rìn ni à á ko’ni. Èyí ló d’ifá fún ìgbìyànjú àwọn Yorùbá láti tún ara ṣe, láti má rìnrìn ìdọ̀tí, kí olúwarẹ̀ lè ṣe é rí láwùjọ. Yorùbá tí ń wọ aṣọ oríṣiríṣi kí àwọn àjòjì tàbí òyìnbó tó dé ilẹ̀ wa, bẹẹ sì ni wọn kò wo […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀWỌN TÍ WỌ́N PE’RA WỌN NÍ OLÓRÍ NÍ AFRÍKÀ NI Ọ̀GÁ AGBESÙNMỌ̀MÍ

Ọkùnrin ọmọ ìlú Uganda kan ní ó sọọ́ o, ó ní ìṣòrò Áfríkà ni àwọn tí ó pe’ra wọn ní olórí, ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ àwọn gan-an ni agbésùnmọ̀mí, nítorí àwọn ni wọ́n npàdí àpò pọ̀, pẹ̀lú òyìnbó amúnisìn, láti ta ara ìlú wọn sí ìgbésí ayé ìṣẹ́, látàrí kí àwọn nìkan ṣáà ti ní […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ẹ WÒ Ó BÍ ÀWỌN OLÓṢÈLÚ NÍ ÌLÚ AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÀÌJÍRÍÀ ṢE Ń PANÁ ÒGO ÀWỌN Ọ̀DỌ́

Arábìnrin kan tí ó darapọ̀ mọ́ àwọn ọ̀dọ́ tí ó ń ṣe ìwọ́de ìfẹ̀húnúhàn ní ìlú agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà ní ó ti pariwo síta báyìí o, wípé, ìyà ti pọ̀jù ní orílẹ̀ èdè àwọn, ilé ìwé ìjọba tí ó yẹ kí ọ́ jẹ́ ọ̀fẹ́, kìí se ọ̀fẹ́ rárá, ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún náírà ní wọ́n ń gbà […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀWỌN Ọ̀DỌ́ ÌLÚ GẸ̀Ẹ́SÌ SỌ WÍPÉ KÍ ÀJÈJÌ Ó KÚRÒ NÍ ÌLÚ ÀWỌN O!

Àwọn ọ̀dọ́ ìlú Gẹ̀ẹ́sì ti dìde o, wọ́n ní ó tó gẹ́ẹ́; àwọn kò fẹ́ àjèjì ní ìlú àwọn; wọ́n ní ó ti wáá sú wọn pátápátá gbáà o! Wọ́n ti nṣe ìwọ́de ní ìlú London, tí wọ́n sì gbé àwọn àsíá ìlú wọn sókè, tí wọ́n nkígbe ní ohùn rara, wọ́n ní “ÀWA FẸ́ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÌGBÀYÍ LÀÁRỌ̀ OBASANJỌ́, T’Ó NSỌ̀RỌ̀ NÍPA EPO RỌ̀BÌ

Olórí àwọn àgbàyà, Olúṣẹgun Àrẹ̀mú Ọbásanjọ́, tí fẹ’nu sí ọ̀rọ̀ èpo rọ̀bi, ó sì sọ ọ̀rọ̀ látàrí bí àwọn tí wọ́n ngbé epo wá sí ìlú wọn Nàìjíríà kò ṣe ní jẹ́ kí ilé-iṣẹ́ ìfọpo Dangote ó rọ́wọ́ mú! Ṣé ó kúkú ti pẹ́ tí a máa ngbọ́ pé Ọbásanjọ́ fún’ra rẹ̀ kàn fi Dangote […]

Read more