Àwọn ọ̀dọ́ ìlú Gẹ̀ẹ́sì ti dìde o, wọ́n ní ó tó gẹ́ẹ́; àwọn kò fẹ́ àjèjì ní ìlú àwọn; wọ́n ní ó ti wáá sú wọn pátápátá gbáà o!

Wọ́n ti nṣe ìwọ́de ní ìlú London, tí wọ́n sì gbé àwọn àsíá ìlú wọn sókè, tí wọ́n nkígbe ní ohùn rara, wọ́n ní “ÀWA FẸ́ ÌLÚ WA PADÀ, ÀWA FẸ́ ÌLÚ WA PADÀ…” Igbe tí wọ́n nké nìyẹn o!

Ó ti sú wọn pátápátá, wọ́n ní àwọn àjèjì ti gba ìlú àwọn mọ́ wọn lọ́wọ́, àwọn ò sì fẹ́ àjèjì mọ́. Wọ́n ríi sọ o, nígbàti ọmọ Gẹ̀ẹ́sì kò bá lẹ́nu ọ̀rọ̀ ní ìlú Gẹ̀ẹ́sì mọ́, kíló tún kù?

Gbogbo ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá, ẹ jọ̀wọ́, ẹ gbárùkù ti Ìjọba Adelé Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, lábẹ́ àkóso Olórí-Adelé, Mobọ́lájí Ọláwálé Akinọlá Ọmọ́kọrẹ́, kí Ìjọba-Adelé ó wọ inú Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba wa káàkiri Orílẹ̀-èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá.

The democratic republic of the yoruba is a new sovereign nation from april 12th 2024

Ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá, ẹ jẹ́ kí á gba ilẹ̀ wa pádà, kí ajèjì ó yé fọwọ́ lalẹ̀ fún wa lórí ilẹ̀ Babanlá wa.

Ilẹ̀ Yorùbá, fún ọmọ Yorùbá. Ilẹ̀ Yorùbá, fún Ọmọ Yorùbá!

ILẸ̀ YORÙBÁ, FÚN ỌMỌ YORÙBÁ. Íbò, Fúlàní, Gẹ̀ẹ́sì, kìí ṣe ọmọ Yorùbá! Ọmọ Yorùbá ló ni ilẹ̀ Yorùbá. Àjèjì kò le fí ipá dúró sórí ilẹ̀ wa!

ỌMỌ YORÙBÁ, Ẹ GBÁRÙKÙ TI ÌJỌBA-ADELÉ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TI YORÙBÁ (D.R.Y)