• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
Democratic republic of the Yoruba ominira new update | Yoruba Nation | Newest Nation in Africa, World

Oríṣiríṣi Ọ̀rọ̀ Tí Kò Ní Ìtumọ̀ Láti Ẹnu Àjọ Ecowas!

A kì í ní k’ọ́mọ ẹni má d’ẹ́tẹ̀, tó bá ti lè dá’gbó gbé ECOWAS tún ti gbé tuntun dé o! Àwọn wo ni ECOWAS? Àwọn apapọ̀ orílẹ̀-èdè ní ìwọ̀-oòrùn Áfríkà, tí wọ́n pa ara wọn pọ̀ láti dòwò papọ̀ látàrí kí ọ̀rọ̀ ajé ó lè dẹrùn káàkiri agbègbè náà. Ṣùgbọ́n ṣá o, láti iye […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ó Màṣe Ò! Ọ̀dọ́’mọkùnrin Kan Ṣe’kúpa Bàbá Rẹ̀ Láti Fi Ṣe Ètùtù Ọlà!

Fọ́nrán kan tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ ni a ti rí ọ̀dọ́’mọdékùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ridwan Adewale tí ó sì ń kà bòòròbò, arákùnrin yí ṣe ikú pá bàbá rẹ̀, ó ní òhún fi ṣe ètùtù ọlà nítorí àìríjẹ. Ọ̀dọ́’mọdékùnrin náà ṣeé láàyè wípé, nígbà tí ìyà náà pọ̀ lápọ̀jù ni òhun […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Gómìnà Abíọ́dún  San Míllíọ̀nù Méjì Fún Mi Lẹ́yìn Tí Mo Sọ̀rọ̀ L’orí Àwọn Ọ̀nà Tí Ó Bà Jẹ́ Ní Ìpínlẹ̀ Ògùn

Ọ̀dọ́mọdé olórin, Habeeb Òkìkíolá, tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Portable fi àwòrán kan s’íta lórí ayélujára ní inú ọ̀sẹ̀ tí ó kọjá yí pé òun bá Ọ̀gbẹ́ni Dàpọ̀ Abíọ́dún s’ọ̀rọ̀ nípa bí gbogbo ọ̀nà ṣe ti di kòtò ikú yíká orígunmẹ́rin Ìpínlẹ̀ Ògùn. Kò jọ wá lójú bí wọ́n ṣe ń ná owó ìjọba ní […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Bàlúù Tí Ó Ti Fò Ni Àwọn Ọ̀daràn Agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà Ń Ṣẹ́’wọ́ Sí

À bí ẹ ò rí iṣẹ́ tí èyí tí ó pe’ra rẹ̀ ní Ọọni ti ilẹ̀ Ifẹ̀, Ẹniìtàn Ogunwusi, rán àwọn ìjòyè rẹ̀ jáde lọ sí gbogbo àwọn ọjà ní ilẹ̀ Ifẹ̀. Èdè ẹrú kan ni ó sọọ́ báyi, medicine after death (ẹ má bínú pé mo lo èdè ẹrú). Ìtúmọ̀ ìyẹn ni, bàlúù tí […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Olóṣèlú Nigeria Ni Olùgbọ̀wọ́ Àwọn Aṣekúpani, Ọ̀dàlúrú Ọmọ-Ìta

Ajá Tó Máa Sọnù Kì Í Gbọ́ Fèrè Ọlọ́dẹ Olóṣèlú Nigeria kan, ní ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, Honorable Sanya Omirin, ni ọ̀daràn kan ti dárúkọ rẹ̀ o, gẹ́gẹ́bí ẹni tí ó máa nrán àwọn ní iṣẹ́ ibi, tí ó sì fún àwọn ní ọgbọ̀n ìbọn láti ṣe iṣẹ́ ibi náà. Èyí tí […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Kò Sí Òfò Tàbí Ìnákúna Ní Orílẹ̀-Èdè Yorùbá, Kò Dà Bíi Ti Ìlú Nàìjí Agbésùnmọ̀mí

Ajá Tó Máa Sọnù Kì Í Gbọ́ Fèrè Ọlọ́dẹ Ìyá Ilẹ̀ Yorùbá ti máa nsọọ́ o, kò sí nínáwó ṣòfò ní ìṣèjọba Orílẹ̀-Èdè Yorùbá. Eléyí yàtọ̀ pátápátá gbáà sí ìwà ìlú agbésùnmọ̀mí tí ó fẹ̀gbẹ́ tì wá, èyí tí ìròhìn fi tó wa létí pé, láarín ọdún kan, ní oṣù kẹ́fà ọdún 2023 sí oṣù […]

Read more
Ominira yoruba daily news | the newest nation in the world 2024

Ó Pẹ́ Tí Òyìnbó Ti Nda Ọpọlọ Àwọn Ènìyàn Rú: Àwọn Ni Ó Yan ‘olóyè’ Ní Ilẹ̀ Íbò

Ajá Tó Máa Sọnù Kì Í Gbọ́ Fèrè Ọlọ́dẹ Ṣé àwọn òyìnbó amúnisìn ni ó kúkú so irun iwájú pọ̀ mọ́ ti ìpàkọ́ ní ilẹ̀ Aláwọ̀dúdú, èyí tí ó fa wípé, ní ibi tí wọ́n wá sọ ní orúkọ “nigeria” ní ọdún 1914, nṣe ni wọ́n so Yorùbá pọ̀ mọ́ Íbò àti Hausa, ẹ̀yà ọ̀tọ̀tọ̀ […]

Read more
Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá Tú Àṣírí Babangida, Ọbásanjọ́ Àti Tinubú Sígboro Ayé

Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá Tú Àṣírí Babangida, Ọbásanjọ́ Àti Tinubú Sígboro Ayé!

Tí Ọmọdé Bá Ńjẹ Èèwọ̀ Tí Ẹnìkan Ò Bi Í, Bó Pẹ́ Bó Yá, Ohun Tí Ńbi’ni Ò Ní Ṣàì Bi’ni  Òwe Yorùbá “Mo kí gbogbo ọmọ Yorùbá, lọ́kùnrin, lóbìrin, lọ́mọdé, lágbà, lárúgbó. Gbogbo ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá (I.Y.P) tí ó jẹ́ oníṣòwò, olókòwò, àti oníṣẹ́-ọwọ́, ẹ máa gbáradì, ìjọba wa ti bẹ̀rẹ̀. “Lóni, mo fẹ́ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Àwọn Ọ̀dọ́ Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì Gbàkóso Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin

A kò tíì kó’fá nílé ifa ti ńṣẹ. Ní ìtọ̀kasí ètò ìṣèjọba ti màmá wa Modúpẹ́ọlá Onitiri-Abiọla ṣètò fún orílẹ̀-èdè Democratic Republic of the Yorùbá, àwọn orílẹ-èdè àgbáyé ti ń mú lò lára kékeré ti wọ́n sọ jáde ninu ohun gbogbo tí Ọlọ́run fí rán wọn sí ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá. Àpẹẹrẹ èyí farahàn nínú àwọn […]

Read more