• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ẹ̀KỌ́ LÁRA OṢÙṢÙ ỌWỌ̀

A le pe ìran ni ẹbí, nítorí náà, ẹ jẹ kí á pe ìran Yorùbá tuntun yìí ní ẹbí, ẹ jẹ́ kí a kíyèsí ẹbí, tí ó jẹ́ baba, iya àti àwọn ọmọ wọn tí ẹbí wọn bá ní ìpìlẹ̀ rere, tí gbogbo wọ́n ba sì ni ìfẹ́ ìjìnlẹ̀, a ó ri wípé tí ìfẹ́ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀWỌN ỌMỌ ÍBÒ TÚN TI BẸ̀RẸ̀ SÍÍ KỌJÁ ÀYÈ WỌN: WỌ́N MÁA TẸ́ !

Ìròhìn tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́ fi hàn pé, ẹ̀tẹ́ àwọn ọmọ Íbò lórí ilẹ̀ Yorùbá, kù sí dẹ̀dẹ̀. A kúkú ti mọ̀ wọ́n tẹ́lẹ̀ sí alágídí; bẹ́ẹ̀ ni wọ́n máa nsọ̀rọ̀ láì fi làákàyè si: ṣé wọ́n rò pé Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá jẹ́ Nigeria ni? Dájú-dájú, ọ̀rọ̀ ti kàn wọ́n lára pé […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÒYÌNBÓ AMÚNISÌN NI Ó BẸ̀RẸ̀ YÍYAN YORÙBÁ JẸ !

Bí ẹ̀mí bá gùn, báà kú, ire gbogbo ni í ṣé ojú ẹni  Láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ni ọmọ Yorùbá ti jẹ́ ohun ìríra fún Òyìnbó Amúnisìn, tí ó fi jẹ́ pé, lábẹ́ ìṣàkóso àwọn amúnisìn wọ̀nyí, ohunkóhun tí wọ́n bá fẹ́ ṣe fún àwọn ẹ̀yà tó wà nínú nàìjírà nigbà náà lọ́hun, ti Yorùbá ni […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÈÈMỌ̀! WỌ́N PÈÉ NÍ ÌFÈTÒ-SỌ́MỌ́-BÍBÍ, ṣùgbọ́n ètò ìpànìyàn ni

Ṣé ní, ọ̀pọ̀ ọdún s’ẹhìn báyi, ni àwọn òyìnbó, pẹ̀lú agbátẹrù ìlú agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà, nínú èyí tí a ti wá jáde báyi, bẹ̀rẹ̀ sí ṣe ìpolongo ìfètò-sọ́mọ-bíbí, ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn ni wọn ò fura nígbà náà, l’ọhún, pé ó ní iṣẹ́ ibi kan tí wọ́n fẹ́ ṣe. Ẹ jẹ́ kí á rántí, pé, ní àìpẹ́ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÈTÒ ÒWÒ àti ILÉ-IṢẸ́ ṢÍṢE

Ohun kan tí ó dájú fún gbogbo ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá ti Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, ni pé, àfi ẹni tí kò bá fẹ́ ṣe iṣẹ́, nìkan, ni kò ní rí iṣẹ́ tó wùú láti ṣe, tàbí láti dá sílẹ̀, bẹ́ẹ̀ náà ni ó máa rí owó t’ó tó owó ní’di rẹ̀. Ìyá wá, Màmá Modúpẹ́ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÌJỌBA AGBÉSÙNMỌ̀MÍ NÁÌJÍRÍÀ DÁ ÒṢÌṢẸ́ TÍ Ó NTỌRỌ OWÓ NÍ PÁPÁKỌ̀-OFÚRUFÚ DÚRÓ LẸ́NU IṢẸ́

Ní àìpẹ́ yí ni a rí fídíò lórí ẹ̀rọ ayélujára, tí ó fi hàn bí òṣìṣẹ́ àjọ ètò ìrìnnà-wọ̀lú àwọn ìjọba agbésùnmọ̀mí nàìjíríà tí ó njẹgàba lé ilẹ̀ Democratic Republic of the Yoruba, ṣe ntọrọ owó lọ́wọ́ arìn’rìn-àjò kan. Ohun tí a wá gbọ́ nísiìyí ni pé àjọ náà ti dá òṣìṣẹ́ yí dúró fún […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

KÍ NÀÌJÍRÍÀ Ó KÚRÒ LÓRÍ ILẸ̀ YORÙBÁ NI KÓKÓ

Ìròhìn kan tí ó tẹ̀ wá lọ́wọ́, tí a rí fídíò rẹ̀ ní’bi tí oníròhìn kan ti nṣe ìfọ̀rọ̀-wá’ni-lẹ́nuwò pẹ̀lú ìkan nínú àwọn àgbà-òṣìṣẹ́ ìjọba-àná ní ìlú tó f’ẹ̀gbẹ́ tì wá, Nàìjíríà, ni a ti gbọ́ pé láarín àwọn tí ó nṣe ìjọba wọn l’ọhún náà ni àtakò ti máa nd’ojúkọ àwọn tí ó bá […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÈÈMỌ̀ WỌ̀LÚ NÀÌJÍRÍÀ! ÀWỌN Ọ̀DỌ́MỌBÌNRIN ŃTA ẸYIN INÚ WỌN LÁTI RA IRUN ÒYÌNBÓ NÍTORÍ OGE.

Ọ̀dọ́mọbìnrin kan ti ké gbàjarè lórí ẹ̀rọ ayélujára nípa ìwà búburú ọwọ́ àwọn obìnrin ọ̀dọ́ ní ìlú Warri, ìpínlẹ̀ Delta ní ìlú agbèsùnmọ̀mí Nàìjíríà tó fi ẹ̀gbẹ́ tì wá. Lórí fọ́nrán náà, ó wípé ṣe ni wọ́n lọ ńta ẹyin tí ó yẹ kí wọ́n fí bímọ tí wọ́n sì ńfi owó rẹ̀ ra irun […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀJÀKÁLẸ̀ ÀRÙN MPOX: OLÓRÍ ÀJỌ ÌWÒSÀN ÀGBÁYÉ SỌ̀RỌ̀ SÍTA

Olórí Àjọ Ìwòsan ní Àgbáyé ti sọ̀rọ̀ síta nípa àjàkálẹ̀ ààrùn mpox, èyí tí wọ́n sọ pé ó ti ntàn síta kọjá orílẹ̀-èdè Congo, tí wọ́n dẹ̀ nrò pé bóyá ó túbọ̀ lè máa tàn káàkiri Áfríkà àti kọjá Áfríkà pàápàá. Ó ní òun ti pinnu láti gbé ìgbìmọ̀ kan dìde tí ó máa gba […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

Ẹ̀KỌ́ PÀTÀKÌ LÓRÍ Ọ̀RỌ̀ ÌLÚ GẸ̀Ẹ́SÌ: ỌMỌ YORÙBÁ, Ẹ MÁA BỌ̀ N’LÉ

Ṣébí ní àìpẹ́ yi ni a rí bí àwọn ọ̀dọ́ ìlú Gẹ̀ẹ́si ṣe sọ pé àwọn nfẹ́ ìlú wọn padà, àtí pé àwọn àjèjì ti gba ìlú àwọn mọ́ wọn lọ́wọ́. Ọ̀rọ̀ ré o, àwa Ọmọ Yorùbá; ṣebí ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ìgbà ni Màmá wa, Ìránṣẹ́ Olódùmarè, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí Abíọ́lá, ti máa nsọ fún wa pé, […]

Read more