• Oríkò Ilé-Iṣẹ́ Ìjọba, Agodi, Ìpínlè Ìbàdàn (Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ látijọ), D.R.Y
Democratic republic of the Yoruba ominira new update | Yoruba Nation | Newest Nation in Africa, Youngest country in the World 2024

ADÉYẸYÈ ÒGÚNWÙSÌ NTAN ARA Ẹ̀ JẸ, BÍ Ó TILẸ̀ JẸ́ PÉ Ó DÁRA TÍ ÀWỌN ÌPÍNLẸ̀ ÌṢÈJỌBA Ọ̀YỌ́ NPÒNGBẸ ORÍSUN WỌN

Àwọn tí a ti mọ̀ sí ọba tẹ́lẹ̀, kí ó tó dií pé òyìnbó amúnisìn gba ipò kúrò lọ́wọ́ ọba, tí Nàìjíríà kúkú wa fagi le pátápátá ní ọdún ẹgbàá ó dín mẹ́ta-dín-lógójì tí wọ́n sọra wọn di “republic,” tí kò dẹ̀ tún wá sí àyè fún ní Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá, ti wá […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

EWÉ àti EGBÒ NÍ ILẸ̀ YORÙBÁ ṢE PÀTÀKÌ

Ní àti ayébáyé ni àwọn babanlá wa ní ilẹ̀ Yorùbá ti mọ̀ nípa ìlò ewé, egbò, èso, irúgbìn èso, àti oríṣiríṣi ohun ní àyíká wa láti ṣe ètò ìwòsàn ara fún ọmọ Yorùbá. Olódùmarè, nípa ọgbọ́n inú àti ìtọnà, àti ìwádi àwọn baba wa, ni ó fi nkan wọ̀n yí hàn wọ́n. Èyí túmọ̀ sí […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀṢÀ ÌKÍNI NÍ ILẸ̀ YORÙBÁ

Ìkíni jẹ́ ohun tí a máa ń sọ tàbí ṣe láti ṣe àpọ́nlé ènìyàn. Yorùbá ní oríṣiríṣi ọ̀nà tí wọ́n fi ń kíni ní àkókò ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀, lórí ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀ ní àkókò kan tàbí lórí ohun tí ènìyàn ńṣe lọ́wọ́lọ́wọ́,àti fún oríṣiríṣi ayẹyẹ. Ìkíni jẹ́ ọ̀nà kan gbòógì tí àwọn Yorùbá ń gbà […]

Read more
Democratic republic of the Yoruba ominira new update | Yoruba Nation | Newest Nation in Africa, Youngest country in the World 2024

ỌDÚN Ọ̀DỌ́ NÍ ÀGBÁYÉ: GBOGBO Ẹ̀YIN Ọ̀DỌ́ NÍ ÀGBÁYÉ, Ẹ KÚ ỌDÚN O

Òdodo ní gbóríléèdè lékè o, ká fì’mọ̀ ṣ’ọ̀kan, ká jọ gbógo Yorùbá ga, olórin wa kan ló kọọ́ lórin. Ẹyin ọ̀dọ́ wa ní Orílẹ̀-Èdè Democratic Republic of the Yorùbá, ẹyin ni ogo wa lónìí, lọ́lá àti títí láé, gẹ́gẹ́ bí ìyá wa, ìyá ìrọ̀rùn, ìyá adúláwò, ìyá ìran, ìyá ìmọ́lẹ̀, ìyá Yorùbá, ìyá Ọ̀DỌ́, ìyá […]

Read more
Democratic republic of the Yoruba ominira new update | Yoruba Nation | Newest Nation in Africa, Youngest country in the World 2024

ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TI YORÙBÁ, KÍ GBOGBO Ọ̀DỌ́ ỌMỌ ÌBÍLẸ̀ YORÙBÁ NÍ ÒNÍ, ÀYÁJỌ́ ỌJỌ́ ÀWỌN Ọ̀DỌ́

Òní, ọjọ́ kéjìlá, oṣù ògún, ni àyájọ́ ọjọ́ Àwọn Ọ̀dọ́ káàkiri Àgbáyé; Orílẹ̀-Èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá sì kí gbogbo àwọn Ọ̀dọ́ wa, Ọ̀dọ́ Ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá, ní àkókò yí; a kí wa pé a kú àtẹ̀mọ́ra, àti pé, ìgbà díẹ̀ ló kù o, tí ìjọba wa máa wọlé sí àwọn oríkò ilé-iṣẹ́ Ìjọba wa […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÌLÚ ÈKÓ WA TI DI OHUN MÍRÀN LÁBẸ́ ÌJẸGÀBA NÀÌJÍRÍ

Ṣé a tilẹ̀ mọ̀, tẹ́lẹ̀, pé, àti ìgbà tí òyìnbó amúnisìn ti bẹ̀rẹ̀ ìjẹgàba lórí ilẹ̀ Yorùbá, lọ́jọ́ náà l’ọhún ni ohun gbogbo kò ti lọ bí ó ṣe yẹ kó lọ, ṣùgbọ́n, lẹ́hìn èyí tí wọ́n pè ní Òmìnira, ṣebí àwọn tí ó pe’ra wọn ní ọmọ onílẹ̀ ìbá tiẹ̀ ṣe dáadáa; ṣùgbọ́n yàtọ̀ […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

AYÉDÈRÚ ỌTÍ LÍLE TI WÀ NÍ’TA Ò, ỌMỌ YORÙBÁ Ẹ FUN’RA!

Ó lé ní ẹgbẹ̀rún lọ́nà márùndínlọ́gọ́rùn-ún ìgò ọtí líle ayédèrú tí ọkọ̀ àjàgbé kan ń gbé láti orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà lọ sí ilẹ̀ adúláwọ̀ o, ṣùgbọ́n tí ó jẹ́ wípé Olódùmarè tú wọn ní àṣírí tí wọ́n sì ti gba ọkọ̀ àjàgbé náà sílẹ̀ báyìí fún ìwádìí. Gẹ́gẹ́ bí a ti ṣe gbọ́ nínú ìròyìn […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀṢÍRÍ ÀWỌN ÒYÌNBÓ AMÚNISÌN TÚN TI TÚ: ṢÙGBỌ́N A TI LỌ NÍ TI’WA !

Láìpẹ́ yí ni ìròhìn kan tún tẹ̀ wá lọ́wọ́ o, lórí ìgbésẹ̀ ìkọ̀kọ̀ kan tí àwọn òyìnbó amúnisìn tún ngbé, látàrí kí Áfríkà ṣáà máa sin àwọn; ṣùgbọ́n irọ́ ni wọ́n npa! Yorùbá ti lọ ní ti’wa; ṣúgbọ́n a máa ṣe àlàyé ọ̀rọ̀ náà, kí ó le yé wa yékéyéké, àti kí á le mọ […]

Read more