SEYI MAKINDE, Ẹ̀ṢẸ̀ RẸ̀ Ń PỌ̀ SÍ LÓJOOJÚMỌ́
Seyi Makinde, àti gbogbo ẹ̀yin tí ẹ pera yín ní àgbà, àgbà òfò, ní ilẹ̀ Yorùbá, pẹ̀lú ẹ̀yin tí ẹ pe ara yín lọ́ba, ní ilẹ̀ Yorùbá, ṣùgbọ́n tí ẹ lọ ńrán àwọn èèyàn sí awon ọmọ Yorùbá tí ẹ jí gbé, pẹ̀lú àwọn ọmọ-ogun Orílẹ̀-Èdè wa, Democratic Republic of the Yoruba, tí ẹ jígbé, […]