ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: IBI TÓ BÁ WU I.Y.P LÓ LE GBÉ NÍ D.R.Y
Ọ̀kan lára àwọn àǹfààní tí a óò jẹ ní Orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá, D.R.Y) ni pé ibi tó bá wu oníkálukú ló le gbé ní ilẹ̀ Yorùbá. Gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí màmá wa ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla bá wa sọ láìpẹ́ yí wípé, kò sí ẹlẹ́yàmẹ̀yà ní ilẹ̀ […]