D.R.Y KÒ DÚRÓ SÍNÚ ÒKÙNKÙN MỌ́
Fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ni orílẹ̀ èdè Olómìnira Tiwantiwa ti Yorùbá (Democratic Republic of the Yorùbá D.R.Y) ti wà nínú òkùnkùn látàrí ìwà àti ìṣe àwọn tí wọ́n pe’ra wọn ní adarí tàbí aṣíwájú pàápàá àwọn olóṣèlú ìlú agbésùnmọ̀mí Nàìjíríà. Wọn ò jẹ́ kí a mọ púpọ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ tó ń ṣẹlẹ̀ ní orí ilẹ̀ wa. Wọ́n […]