Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ỌGBỌ́N ÀTINÚDÁ WA

Láti ìgbà ìwásẹ̀ ni àwọn babańlá wa ti ń lo ọgbọ́n àtinúdá wọn láti mú ayé rọrùn fún ara wọn. Ọgbọ́n nípa aṣọ wíwọ̀, oge ṣíṣe, iṣẹ́ ọnà, ìkòkò mímọ, ilà kíkọ, ìlù lílù, ère gbígbẹ́, apẹ̀rẹ̀ hínhun, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ. A ma ṣe àwárí ara wa ní kété tí àwọn Alákóso wa bá ti […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÌTÚSÍLẸ̀ FÚN GBOGBO ẸLẸ́WỌ̀N

Màmá wa, Ìránṣẹ́-Olódùmarè sí Ìran Yorùbá, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá, tún ti rán àwa Ọmọ Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P) ti Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y) létí, ní àìpẹ́ yí, pé, gẹ́gẹ́bí àwọn ṣe sọ fún wa ní ìgbà kan rí, wọ́n ní kété tí àwọn Alákoso-Adelé wa, bá ti wọ inú oríkò-ilé-iṣẹ́-ìṣàkóso wa […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ẸWÀ ÈDÈ YORÙBÁ

Orílẹ̀ èdè tó bá ti sọ èdè rẹ̀ nú yóò parun, ká dúpẹ́ fún Olódùmarè tí ò jẹ́ kí ìran Yorùbá parun. Títí láé ni àwa ìran Yorùbá yóò máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Olódùmarè tó rán ẹni bí ọkàn Rẹ̀ sí wa, màmá wa ìyá ààfin Modupẹọla Onitiri-Abiọla láti mọ ìtúmọ̀ èdè tí ò lẹ́̀ kí […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀWỌN AMÚNISÌN Ń LO ÀWỌN GBAJÚMỌ̀ ILẸ̀ YORÙBÁ

Tí ò bá sí olè ilé, olè ìta kò le jà! Ọ̀rọ̀ yí ló dífá fún bí àwọn amúnisìn ṣe lo àwọn tí wọ́n pe’ra wọn ní gbajúmọ̀ ilẹ̀ Yorùbá láti máa tako òmìnira ilẹ̀ Yorùbá. Wọ́n kọ́kọ́ da àwọn gbajúmọ̀ yí ní ọpọlọ rú, wọn jẹ́ kí wọ́n rò wípé ohun gbogbo tó bá […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: ÌTỌ́JÚ FÚN ỌMỌ ÒRUKÀN

Ànfààní tí ó wà fún Ọmọ-Ìbílẹ̀ Yorùbá (Indigenous Yoruba People, I.Y.P) ti Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y) kò lónkà! Tí a bá ní kí a máa wòó lọ́kan-ò-jọ̀kan, ọpẹ́ lóyẹ kí á máa dá lọ́wọ́ Olódùmarè tí Ó gbé Àlàkalẹ̀ Rere fún Ìran Ọmọ Yorùbá, tí Ó sì tún wá jínkí wa pẹ̀lú Olùgbàlà, […]

Read more
The youngest nation in the world is the democratic republic of the Yoruba. The 55th nation in Africa

ÀWỌN BỌ̀RỌ̀KÌNÍ-OLÓYÌNBÓ TI TẸ́

Tí Olódùmarè bá ti ṣí’jú wo’ni, àyọ̀ ayérayé ni ó máa njẹ́! Olódùmarè ti sí’jú wo ọmọ-Yorùbá ní àkókò yí, títí òpin ayé, nípasẹ̀ iṣẹ́ tí Ó fi rán Màmá wa, Ìyá-Ààfin Modúpẹ́ Onítirí-Abíọ́lá sí àwa Ìran Yorùbá. Èyí ni ó dífá fún ọ̀rọ̀ tí Màmá wa bá wa sọ nípa àwọn tí ó pera […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ÀǸFÀÀNÍ ORÍLẸ̀-ÈDÈ OLÓMÌNIRA TIWANTIWA TÍ YORÙBÁ: Ẹ̀TỌ́ WA GẸ́GẸ́BÍ I.Y.P

Ní Orílẹ̀ èdè Democratic Republic of the Yoruba, D.R.Y, gbogbo wa la mà mọ ẹ̀tọ́ wa, a kò ní jìyà ǹkankan ní ilẹ̀ wa. Nínú àlàkalẹ̀ ètò ìṣàkóso D.R.Y ìkan nínú àwọn ohun tí àwọn Alákòóso wa yíó tètè ṣiṣẹ́ lé ni mímọ ẹ̀tọ́ ẹni gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìbílẹ̀ Yorùbá I.Y.P  Màmá wá, Olóyè Ìyá […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

I.Y.P Ẹ DÌDE, ÌYÀ YÍ TÓ GẸ́Ẹ́!

Oníṣègùn Ìtọ́jú-Àwọn-Ọmọdé kan, ní ìlú Ìbàdàn, Democratic Republic of the Yoruba (D.R.Y), níbití agbésùmọ̀mí Nàìjíríà tí ń jẹ gàba, Dókítà Folúṣọ́ Balógun, ní ó ké gbàjarì, tí ó fí ọ̀rọ̀ yí léde; ó sọ pé, fún ìgbà-àkọ́kọ́ láti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́yìn, ohun abàmì kan nṣẹlẹ̀ ní Ilẹ̀ Yorùbá. Gẹ́gẹ́bí oníṣègùn, ọ̀rọ̀ náà ṣe-é ní kàyéfi! […]

Read more
Democratic Republic of the Yoruba is known in history as Yoruba Kingdom, Yorùbá Nation, Yorubaland, and Yorùbá Country.

ỌBA TANÍ KÓ FẸ́NI LÓJÚ TÓ Ń FI ATA SẸ́NU

Ní ìgbà ìwáṣẹ̀, kí àwọn amúnisìn tó wá so irun iwájú pọ̀ mọ́ ti ìpàkọ́, ọwọ́ àwọn ọba ilẹ̀ Yorùbá ni agbára, àṣẹ àti ìdarí ohun gbogbo wà. Ohun tí wọ́n bá sọ fún àwọn ará ìlú nígbà náà ni wọ́n ń ṣe, èyí ló mú kí wọ́n wá rí ara wọn bí i igbákejì […]

Read more