BLACK LION F’ÈSÌ FÚN ẸNI T’Ó PE’RA RẸ̀ L’ỌBA O!
L’atàrí ìròhìn tí ó já’de l’aná òde yí, wípé kò sí ọba ní ilẹ̀ Yorùbá, ẹni kan tí ó ṣì rò wípé ọba ni òun, ti kàn sí ojúlówó ọmọ Yorùbá, BLACK LION, o! Ẹni náà wá nsọ wipé ọmọ Yorùbá sọ wípé àwọn ò fẹ́ ọba ní ilẹ̀ Yorùbá BLACK LION wá da l’ohùn […]