Ẹ JẸ́ KÍ Á FURA
Ẹni tí kò bá mọ̀ tẹ́lẹ̀, kí ó yára mọ̀ báyi – àwọn òyìnbó amúnisìn fẹ́ pa áfríkà run ni, kí àwọn lè wá jóko sí orí-ilẹ̀ wa, nítorí ilẹ̀ wa ni oríṣiríṣi ohun-àmúṣọrọ̀ wà (resources). Òyìnbò ò kì nṣe ọ̀rẹ́ aláwọ̀dúdú, ìyẹn ni kí a jẹ́ kí ó yé wa, dáradára. Nítorí náà, ẹ […]